Jọkẹ Amọri Beeyan ba gẹṣin ninu arẹwa oṣere ilẹ wa to lomi lara daadaa nni, Temidayọ…
Ayedatiwa wọle ibo gomina l’Ondo
Ajọ eleto idibo ilẹ wa ti kede gomina ipnlẹ Ondo to wa lori aleefa bayii, Ọgbẹni…
Ẹgbẹ oṣelu APC lo wọle gbogbo idibo ijọba ibilẹ ipinlẹ Ogun
Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹgbẹ oṣelu Onigbaalẹ, All Progressives Congress (APC), lo jawe olubori ninu gbogbo ipo…
Wọn le Emmanuel danu lẹnu iṣẹ ologun, lo ba n faṣọ wọn ṣiṣẹ ajinigbe
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ Emmanuel Anthony, ẹni ọdun mẹrinlelọgbọn, lori…
Ọga ọlọpaa patapata, Kayọde Ẹgbẹtokun, gba awọn ọmọ Naijiria nimọran
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọga agba awọn ọlọpaa patapata lorilẹ-ede yii, IGP Kayọde Ẹgbẹtokun, ti ṣalaye ohun…
Ẹgbẹ awọn adajọ orileede yii da meji ninu wọn duro lẹnu iṣẹ
Adewale Adeoye Ni bayii, ẹgbẹ awọn adajọ lorileede yii, ‘National Judicial Council’ (NJC) labẹ iṣakoso olori…
Ileeṣẹ ọlọpaa Eko fẹ ba ọmọ orileede China to ya owo naira pẹrẹpẹrẹ nita ṣẹjọ
Adewale Adeoye Awọn agba bọ wọn ni ko si awijare kankan fẹni to faṣọ ọlọpaa gba…
Ẹ gba wa o, ẹgbẹ oṣelu APC ti ko tọọgi wọ gbogbo abule to wa nijọba ibilẹ Idanre-Akíngbàsọ̀
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbakeji gomina fun oludije ẹgbẹ Peoples Democratic Party (PDP) ninu eto idibo gomina…
Eto idibo ijọba ibilẹ Ogun: Awọn oludibo fabinu yọ ni Ṣagamu, eyi lohun ti Gomina Abiọdun ṣe
Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi eto idibo ijọba ibilẹ ṣe n lọ lọwọ jake-jado ipinlẹ Ogun,…
Ile-ẹjọ yẹ aga nidii MC Oluọmọ, wọn ni Baruwa lo yẹ nipo naa
Ọrọ Yoruba kan ti wọn maa n sọ pe, ‘ọba ki i pe meji laafin’…
Eyi ni bi wọn ṣẹ yinbọn pa oludije sipo kanselọ lo ku diẹ ki eto idibo waye l’Ogun
Ọlawale Ajao, Ibadan Nigba tawọn ara ipinlẹ Ogun n mura lati jade lọọ dibo ijọba ibilẹ…