Monisọla Saka Ọwọ ijọba ipinlẹ Eko ti tẹ awọn afurasi mẹrinlelaaadọrun-un, lasiko tileeṣẹ to n ri…
Asiri ọna tawọn ẹgbẹ APC fẹẹ fi ṣeru ninu eto idibo to n bọ yii ti tu si wa lọwọ- PDP
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Bi eto idibo gomina to fẹẹ waye lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu…
Nitori eto idibo to n bọ, eyi lohun tijọba Ondo ṣe fawọn oṣiṣẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ijọba ipinlẹ Ondo ti kede ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu Kọkanla, ọdun…
A maa too kapa awọn ẹgbẹ afẹmiṣofo ti wọn ṣẹṣe jade lorileede yii- Tinubu
Adewale Adeoye Ki i ṣe iroyin mọ rara pe ẹgbẹ afẹmiṣofo tuntun kan ti wọn n…
Ibo ọdun 2027: Ko saaye rara fun Atiku – Wike
Adewale Adeoye Minisita ilu Abuja, to tun jẹ ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP,…
Eyi ni bijọba Makinde yoo ṣe na ọrinlelẹgbẹta biliọnu Naira to gbe lọ sileegbimọ aṣofin fun eto iṣuna ọdun 2025
Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, biliọnu lọna ọrinlelẹgbẹta o din meji (678b) lapapọ owo ti…
Ọwọ tẹ Ẹnitan to ji ara rẹ gbe nitori ko ma baa san gbese to miliọnu kan Naira to jẹ
Adewale Adeoye Nitori gbese miliọnu kan Naira ti baale ile kan, Ọgbeni Ẹnitan Awoyẹmi, ẹni ọdun…
Wọn ti mu awọn ọmọ Naijiria yii nilẹ Libya
Adeoye adewale Mẹta lara awọn ọmọ orileede Naijiria kan ti wọn n gbe niluu Al-Khums, lorileede…
Akẹkọọ tawọn ọlọpaa pa n’llọrin, ki i ṣe ọmọleewe wa- KWASU
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn alaṣẹ ileewe Fasiti tipinlẹ Kwara (Kwara State University), to wa niluu Malete,…
Nnkan de, araalu koju ija sawọn oṣiṣẹ LASTMA l’Ekoo eyi lohun to fa a
Adewale Adeoye Fun bii wakati mẹta ni wahala, idarudapọ ati laaṣigbo nla fi bẹ silẹ ni…
A ti la oke iṣoro to ga ju lọ kọja lorileede yii, ka maa gbadun lo ku – Aarẹ Tinubu
Adewale Adeoye Awọn agba bọ, wọn ni bo ba pẹ ta a ti n da obi,…