Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan mẹta ni wọn pade iku ojiji niluu Ọwọ, ti i ṣe ibujokoo…
Author: admin
Idajọ kootu: Tinubu, Oyetọla ki Adeleke ku oriire
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Aarẹ tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan lorileede Naijiria, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu,…
Oṣelu ti kọja bayii, ka fọwọsowọpọ fun idagbasoke Ọṣun lo ku – Gomina Adeleke
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, ti ke si gbogbo awọn eeyan ipinlẹ…
Gomina Makinde ko gbọdọ ti i fi ẹnikẹni jẹ Alaafin lasiko yii-Idile ọmọọba Ọyọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn idile ọba Alaafin Ọyọ mẹsan-an ti rawọ ẹbẹ si Gomina ipinlẹ Ọyọ,…
Ẹwọn n run nimu Quadri yii o, Qudus lo gun lọbẹ pa l’Ekoo
Faith Adebọla, Eko Ọdọmọkunrin kan ti wọn porukọ ẹ ni Quadri Raji Arẹmu, ti ko ara…
Ọlọpaa gba eeyan mejilelogun silẹ lọwọ ajinigbe
Faith Adebọla Iku ti iba pa ni, bo ba ṣi ni ni fila, o yẹ ka…
Biliọnu mẹrinla Naira ni wọn yoo fi tun Aso Rock ṣe silẹ de Tinubu
Monisọla Saka Ni ipalẹmọ fun ayẹyẹ eto iburawọle fun aarẹ tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan…
Ẹfun abeedi! Abdulwahab fibinu lu ọmọ rẹ pa nitori ọka-baba
Adewale Adeoye Awọn alaṣe ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kano ti sọ pe awọn ti gbọ si iṣẹlẹ…
Ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹta fiku ṣefa jẹ, ọlọpaa ni wọn doju ija kọ
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Rivers, ti sọ pe mẹta lara awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun kan…
Ijọba Eko bẹrẹ ayẹwo fawọn to n lọ silẹ Mẹka
Adewale Adeoye Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe yẹ, ọjọ Aje. Monde, ọjọ kẹjọ, oṣu…
Mi o fẹẹ ri awon to n gbe egboogi oloro ati ọmọ ẹgbẹ okunkun mọ nipinlẹ Ogun-Abiọdun
Faith Adebọla Bi asiko kan ba wa ti Ọmọọba Gomina ipinlẹ Ogun koro oju gidigidi, ti…