Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ogunṣua ti ilu Mọdakẹkẹ, Ọba Joseph Olubiyi Toriọla, ti ke si gbogbo awọn…
Category: Ìròyìn
Ọpọ ẹmi ṣofo nibi ijamba ọkọ oju omi to ṣẹlẹ
Monisọla Saka Ko din ni ogun eeyan, ti pupọ ninu wọn si jẹ obinrin ati ọmọde,…
Alaga wa ko ku o, awọn ọta rẹ lo wa nidii ibajẹ yii- INEC
Adewale adeoye ‘Kokooko lara ọta ọga wa le, ko sohun to ṣe alaga ajọ eleto idibo…
Mi o ran ẹnikẹni pe ki wọn lọọ bẹ Afẹ Babalọla fun mi o-Dele Farotimi
Taofiq Surdiq, Ado-Ekiti ‘’Bi ẹnikẹni ba loun n lọọ bẹ Aarẹ Afẹ Babalọla nitori ọrọ ija…
Iya nla la maa fi jẹ banki to ba ta owo Naira tuntun fawọn alaarobọ-CBN
Adewale adeoye Ilu ti ko ba sofin, ẹṣẹ ko si nibẹ, bi ofin ba ti de,…
Oniwaasi agbaye nni, Sheik Muyideen Ajani Bello, ti jade laye o
Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe baba naa ki i ṣe ọmọde, nitori o ti le…
NAFDAC tileeṣẹ ti wọn ti n ṣe ayederu ọti waini pa l’Ekoo
Adewale adeoye Ọwọ oṣiṣẹ ajọ to n ri sọrọ ounjẹ jijẹ ati ohun mimu lorileede yii,…
Awọn ọdọ ṣewọde ifẹhonuhan l’Abuja, eyi lohun to n bi wọn ninu o
Adewale adeoye Awọn ọdọ langba kan ti wọn n ṣewọde ifẹhonuhan l’Abuja, lati kilọ fawọn araalu…
Eyi nidi ti owo epo bẹntiroolu ko ṣe ni i wa silẹ lasiko yii – PENGASSAN
Adewale adeoye Aarẹ ẹgbẹ oṣiṣẹ ileeṣẹ epo bẹntiroolu lorileede yii. ‘Petroleum And Natural Gas Senior Staff…
O ga o, eyi lohun tawọn aṣofin ṣe fun Dapọ Abiọdun nigba to gbe aba eto iṣuna ọdun 2025 lọ siwaju wọn
Ọlawale Ajao Owo ti apapọ rẹ jẹ tiriliọnu kan ati biliọnu marundinlọgọta Naira (₦1.055 trn) nipinlẹ…
Eyi lohun to ṣẹlẹ ni kootu lasiko igbẹjọ gomina Kwara tẹlẹ
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ko sẹni to de ayika ile-ẹjọ giga ijọba apapọ, iyẹn Federal High Court,…