Ijọba tileetaja igbalode kan pa l’Ekoo, ọja to ti bajẹ ni wọn n ta nibẹ

Adewale adeoye Ni bayii, titi pa patapata ni nijọba ipinlẹ Eko ti ileetaja igbalode kan ti…

O ma ṣe o, ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Mercy Aigbe

Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe ipolowo fiimu rẹ ti yoo jade ninu oṣu yii ni…

Ki Tinubu ro o daadaa o, abadofin owo-ori tuntun yii maa fiya jẹ awọn eeyan Oke-Ọya- Zulum 

Adewale adeoye Gomina ipinlẹ Borno, Babagana Zulum, ti ni awọn ara Oke-Ọya ko ta ko pe…

NSCDC Kwara ti doola ẹmi akẹkọọ Fasiti Kogi ti wọn ji gbe

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Mọnnde, ọjọ kẹta, oṣu Kejila, ọdun 2024 yii, ajọ ṣifu difẹnsi,…

Emi ni mi o jẹ ki Abacha pa Ọbasanjọ – Gowon

Monisọla Saka Olori ilẹ wa nigba kan ri, General Yakubu Gowon, ti ni oun ni Ọlọrun…

O ṣẹlẹ! Owo lawọn ọmọ Naijiria yoo fi maa ṣe NIN bayii

Monisọla Saka Ajọ to n ri si ọrọ kaadi idanimọ lorilẹ-ede yii, National Identity Management Commission…

Ọlọkada yii loun ko fẹẹ ri ọdun 2025, eyi lohun to ṣe funra ẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nigba ti gbogbo aye n gbadura lati la ọdun 2024 to n pari…

  Awọn eto ọrọ aje ta a n ṣe atunṣe rẹ ti bẹrẹ si i so eeso rere –Aarẹ Tinubu

Adewale adeoye ‘‘Bi ẹkun ba dalẹ ni, ayọ ati ireti ọtun n bọ lowurọ, diẹ lo…

Orileede Brazil ni ọmọ Naijiria yii ti n gbe kokeeni bọ ti wọn fi mu un n’Ikẹja

Adewale adeoye Ọdọ ajọ to n gbogun ti gbigbe ati lilo egboogi oloro lorileede yii, ‘National…

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Adekunle o, ọgẹdẹ lọọ ji loko oloko

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti mu ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn kan, Adekunle Omideyi,…

L’Ọṣun, oṣiṣẹ aṣọbode, iyawo atawọn ọmọ ẹ mẹrin jona mọle

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oṣiṣẹ aṣọbode kan ni ẹka ileeṣẹ naa nipinlẹ Ọyọ ati Ọṣun, Tijani Kabiru,…