Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, mẹfa ninu awọn olukọ ileewe girama to jẹ tijọba ipinlẹ…
Author: admin
Ibo gomina Ọṣun: Ile-ẹjọ to ga ju lọ yoo gbe idajọ kalẹ lọjọ Tusidee
Faith Adebọla Ile-ẹjọ to ga ju lọ nilẹ wa, Supreme Court, ti kede pe ọjọ Iṣẹgun,…
Igbẹjọ bẹrẹ lori awuyewuye eto idibo aarẹ, Peter Obi moju aara ẹ de kootu
Adewale Adeoye Ile-ẹjọ to n gbọ ẹjọ ẹsun to jẹ yọ lakooko eto idibo aarẹ nilẹ…
Mọto mọkanla atawọn nnkan olowo nla mi-in ni wọn ba lọwọ ọmọ Yahoo tọwọ tẹ n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọwọ ajọ to n gbogun ti iwa magomago ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku,…
Gowon gba Atiku ati Obi nimọran lori ẹjọ idibo aarẹ ti wọn pe
Faith Adebọla Olori orileede yii lasiko iṣejọba ologun, Ajagun-fẹyinti Yakubu Gowon, ti gba oludije funpo aarẹ…
Lẹyin ti Mọjeed ti ọgba ẹwọn de lo tun lọọ ji ọkada mẹrin l’Oṣogbo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan bayii ni tolohun lọrọ da fún ọmọkunrin…
Ki i ṣe ojuṣe ijọba lati pese iṣẹ faraalu o – Fẹmi Adeṣina
Faith Adebọla Oludamọran pataki si Aarẹ Muhammadu Buhari lori eto iroyin ati ikede, Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina,…
Tọkọ-taya yii ji ara wọn gbe pamọ, wọn fẹẹ fi gbowo lọwọ mọlẹbi wọn
Faith Adebọla, Eko Bii ẹni n ṣere ori itage lọrọ naa jọ, ṣugbọn ki i ṣe…
Pasitọ fun ọmọ ijọ mẹwaa loyun lẹẹkan naa, ni wọn ba le e kuro niluu
Faith Adebọla Pasitọ oniṣẹ-iyanu lawọn eeyan mọ ọn si, titi dasiko ta a si fi n…
Emi ni mo pa baba mi, ẹmi kan lo ni ki n lọọ la irin mọ wọn lori latoju-oorun- Ismail
Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ọfọ ati airoju ni gbogbo mọlẹbi kan torukọ idile wọn n jẹ…
Lẹyin ti wọn pa meji ninu wọn, awọn ajinigbe tu eeyan mẹrinlelaaadọrin silẹ lọjọ kan ṣoṣo
Monisọla Saka Mẹrinlelaaadọrin, ninu eeyan tawọn agbebọn ji gbe labule Wanzamai, nijọba ibilẹ Tsafe, nipinlẹ Zamfara,…