Wọn ma ni wọn ko ri ọmọkunrin adẹrin-in poṣonu nni, Cute Abiọla

  Titi di ba a ṣe n sọ yii ni wọn ṣi n wa ọkunrin adẹrin-in…

Ori ko awọn oṣiṣẹ panapana yọ lọwọ iku ojiji ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, lori ko awọn oṣiṣẹ ajọ panapana nipinlẹ Kwara yọ…

Ile alaja mọkanlelogun wo le awọn to n ṣiṣẹ nibẹ lori l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko  Titi dasiko yii ni ko ti i sẹni to le sọ pato ipo…

Onifayawọ meji ku, aṣọbode meji fara pa, lasiko ti wọn koju ara wọn nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ ti ikọlu ti n waye laarin awọn onifayawọ ati aṣọbode nipinlẹ Ogun,…

Taiwo bimọ fun Kẹhinde ẹ lẹẹmẹji, o loun maa n gbadun ‘kinni’ ekeji oun

Faith Adebọla Ọrọ buruku toun tẹrin lọrọ naa jọ, palapala ilu apala ni, ṣugbọn eegun to…

Adajọ ti ju Aafaa to forukọ ọmọọṣẹ Buhari lu jibiti sẹwọn ọdun mejidinlọgbọn n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni Onidaajọ Mahmud Abdulgafar tile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin,…

O yẹ kawọn gomina Guusu kọkọ ba awa ti Ariwa sọrọ ki wọn too ṣe ipinnu lori agbegbe ti aarẹ yoo lọ – El-Rufai

Faith Adebọla   Gomina ipinlẹ Kaduna, Mallam Nasir El-Rufai ti sọ pe awọn gomina ipinlẹ Ariwa ko…

Ọlọpaa ti mu Okoye to binu de onigbese rẹ mọ’gi bii ẹran iso l’Ebute-Mẹta

Faith Adebọla, Eko Ọpẹlọpẹ awọn ọlọpaa ti wọn tete de ibi iṣẹlẹ ọhun, boya ori iso…

Awọn agbebọn ji iya at’ọmọ ẹ meji gbe l’Omu-Aran 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ yii, ni awọn agbebọn ya bo agbegbe ikorita Oko,…

Arẹgbẹsọla rọ awọn ẹlẹwọn to sa lọ ni Kogi lati pada sọgba ẹwọn kiakia

Faith Adebọla, Eko Minisita fun ọrọ abẹle, Ọgbẹni Rauf Aregbẹṣọla, ti ṣekilọ fawọn ẹlẹwọn ti wọn…

Ara Iyabo Oko onitiata ko ya gidigidi,  o nilo iranlọwọ ọmọ Naijiria

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lasiko ti a n kọ iroyin yii lọwọ, inu aarẹ nla ni agba…