Erin wo! Ọwa Obokun ilẹ Ijẹṣa waja

Florence Babaṣọla, Oṣogbo

Ọwa Obokun ilẹ Ijẹsa, Ọba Gabriel Adekunle Aromọlaran, ti waja.

Ọdun mẹtadinlaaadọrun-un ni baba naa lo lori eepẹ ko too darạpọ mọ awọn baba nla rẹ nirọlẹ Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹsan-an, ọdun yii.

Ọdun mejilelogoji ni baba naa lo lori itẹ ko too waja.

 

Leave a Reply