Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oju bọrọ ko ṣee gbọmọ lọwọ ekurọ lọrọ naa da fun awọn agbofinro…
Author: admin
Lati din bawọn araalu ṣe n mu un ku, ijọba fẹẹ fi kun owo-ori siga
Adewale Adeoye Bi ọrọ to n jade lẹnu awọn alaṣẹ ijọba apapọ ilẹ yii ba jẹ…
Iyawo ṣoniduuro fọkọ ẹ, niyẹn ba sa lọ, lọrọ ba di keesi
Adewale Adeoye Afaimọ ni iyaale ile kan to ṣe oniduuro fun ọkọ rẹ lori gbese to…
Ṣọja yinbọn pa ọlọpaa to da ọkọ ti ọkan ninu wọn ko igbo sinu rẹ duro
Monisọla Saka Ọkunrin agbofinro kan, Ahmed Ali, ti ṣe bẹẹ ki aye pe o digbooṣe lẹyin…
Ọmọ ọdun mejidinlogun dero ile-ẹjọ, ileeṣẹ panapana lo n mu ṣere
Monisọla Saka Ijọba ipinlẹ Eko ti wọ ọmọkunrin ẹni ọdun mejidinlogun (18) kan, Uzuokwu Solomon, lọ…
Awọn ajinigbe yinbọn pa Musa, nitori ti ko jẹ ki wọn jiyawo ẹ gbe lọ
Monisọla Saka Awọn ajinigbe ti da ẹmi ọkunrin kan, Musa Abari Kusaki, legbodo, lasiko ti wọn…
Aafaa Atidade n leri pe oun yoo pa awọn ọlọpaa n’Ibadan, ni wọn ba wọ ọ lọ si kootu
Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori to dunkooko iku mọ awọn agbofinro ti wọn wa lẹnu iṣẹ oojọ…
Ile-ẹjọ yẹ aga nidii MC Oluọmọ, wọn wọgi le igbimọ alakooso gareeji to n dari
Faith Adebọla, Eko Ile-ẹjọ giga to n ri si ọrọ awọn ileeṣẹ ati ẹgbẹ nilẹ wa,…
Rafiu oni POS wọ wahala: Wọn ṣeeṣi san miliọnu rẹpẹtẹ sinu akaunti ẹ, o ra ile, o ra mọto, o tun ran awọn eeyan ni Umrah
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Arakunrin kan to n ṣowo POS, Aafaa Rafiu Akuji, to n gbe ni…
Ọrẹ meji dero ẹwọn ni Kwara, ọrẹ wọn ni wọn lu pa nitori ẹgbẹrun mẹrindinlọgọta Naira
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileesẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, ti fi panpẹ ofin gbe awọn gende meji kan,…
Ibo gomina Adamawa: Ọjọ Tọsidee la maa kede ẹni to jawe olubori-INEC
Faith Adebọla Awuyewuye to bẹ silẹ lori atundi idibo sipo gomina nipinlẹ Adamawa, eyi to waye…