Monisọla Saka Pẹlu bi Donald Trump, ṣe wọlẹ ibo gẹgẹ bii Aarẹ ilẹ Amẹrika lẹẹkeji, Aarẹ…
Author: admin
Bobrisky ti sọrọ o: Eyi nidi ti mo ṣe sa lọ siluu oyinbo
Adewale Adeoye Gbajumọ ọmọ jayejaye to nifẹẹ lati maa mura bii obinrin nni, Idris Okunẹyẹ, ẹni…
Ileeṣẹ Dangote tu aṣiri nla: NNPCL ko ni irinṣẹ ti wọn fi le da ayederu epo bẹntiroolu mọ
Adewale Adeoye Ba a ba dakẹ, tara ẹni aa ba ni dakẹ, nileeṣẹ ifọpo to ṣẹṣẹ…
O ma ṣe o! Lagbaja, ọga awọn ṣọja patapata nilẹ wa ti jade laye
Monisọla Saka Ọgagun Taoreed Abiọdun Lagbaja, ti i ṣe olori awọn ṣọja, ti pada faye silẹ.…
Opo to n pin ina fun gbogbo Naijiria ti tun daṣẹ silẹ o
Monisọla Saka Opo to n pin ina fun gbogbo ilẹ Naijiria tun ti daṣẹ silẹ. Lati…
Ẹ ma ṣepe fawọn adari yin mọ, ẹ fa wọn si kootu Ọlọrun Ọba- Sultan Ṣokoto
Adewale Adeoye Ọkan pata lara awọn Emir nilẹ Arewa, Sultan tilu Ṣokoto, Alhaji Sa’ad Mohamed Abubarkar…
Gbogbo ohun to ba jẹ ojuṣe wa la maa ṣe pata bi asiko ba to – Aarẹ Tinubu
Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti sọ pe gbogbo ohun to ba…
NAFDAC ti ile ileetaja igbalode ti wọn ti n ta ọja to ti bajẹ pa l’Abuja
Adewale adeoye Ni bayii, ajọ to n ri sọrọ ohun jijẹ ati minu lorileede yii, ‘National…
Tinubu bura fawọn minisita meje tuntun l’Abuja
Adewale adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti bura fawọn minisita meje tuntun to…
Adeleke, inira yii pọ o, sanwo oṣu tuntun fawọn oṣiṣẹ ijọba – TOM
Florence Babaṣọla, Oṣogbo The Osun Masterminds (TOM), ti ke si Gomina Ademọla Adeleke lati bẹrẹ si…
Tinubu ti ni ki adajọ agba ilẹ wa ri sọrọ awọn ọmọ keekeeke tijọba n ba ṣẹjọ
Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti paṣẹ fun Minisita eto idajọ lorileede…