Adewale Adeoye Ile-ẹjọ Majisireeti kan to ni agbegbe Ajangbadi, nipinlẹ Eko, niwaju Onidaajọ L.K.J Layẹni, ni wọn wọ Pasitọ ijọ Ọlọrun kan, David Eludi, lọ. Ẹsun…
Category: Ìròyìn
O ma ṣe o, eefin jẹnẹratọ pa ololufẹ meji ti wọn n mura igbeyawo sinu ile
Adewale Adeoye Inu ọfọ nla ni gbogbo awọn olugbe agbegbe Ugborikoko, nijọba ibilẹ Uvwie, nipinlẹ Delta, wa bayii. Ohun to fa a ti…
Ikunlẹ abiyamọ o! Eeyan mẹwaa ku ninu ijamba ọkọ lojuna Marosẹ Eko s’Ibadan
Adewale Adeoye Beeyan ba jori ahun, bo ba ri bi ẹran awọn eeyan kan ṣe ja wẹlẹwẹlẹ, to si…
Akeredolu sọrẹnda, o gbejọba fun igbakeji ẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ O ṣee ṣe ki rogbodiyan oṣelu to n mi ipinlẹ Ondo logbogbo lati…
Aṣifẹ pata gbaa lọkọ ti mo fẹ yii, adajọ, ẹ tu wa ka- Bọla
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ Ọyọ, ni awọn tọkọ-taya meji kan, Ọgbẹni Morufu Dele, ati Abilekọ Bọla Dele, gbẹjọ ara…
O ma ṣe o, iya at’ọmọ padanu ẹmi wọn sinu ijamba ọkọ oju omi
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n koroyin yii jọ lọwọ, awọn alaṣẹ ijọba ilu kan ti…
Ayẹwo ẹjẹ f’ọmọ Mohbad ko si ninu adehun wa lati ja fun oloogbe – Iyabo Ojo
Adewale Adeoye Gbajumọ oṣerebirin onitiata ilẹ wa nni, Iyabo Ojo, ti sọ pe ayẹwo ẹjẹ fun Liam, ọmọ Ilerioluwa Alọba ti gbogbo…
Ọmọlokùn kan ree o, Sadiq yinbọn pa iya ẹ, o lajẹẹ ni
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Boga, nipinlẹ Adamawa, ti mu Ọgbẹni Sadiq Idrissu, ẹni ọgbọn ọdun, to pa iya rẹ lẹyin to fẹsun kan an…
Wahala ree o! Awọn akẹkọọ mejidinlogun jẹ majele ninu ounjẹ nileewe l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo O kere tan, awọn akẹkọọ mejidinlogun ti ileewe St James Primary School B,…
Ọwọ Amọtẹkun tẹ Garuba, ogbologboo ajinigbe to n yọ awọn eeyan Ọ̀sẹ́ lẹnu
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹṣọ Amọtẹkun ti ipinlẹ Ondo ti fi pampẹ ofin gbe ogbologboo ajinigbe kan…
Taya tanka fọ, o ja wọ ṣọọbu oniṣọọbu n’llọrin, eeyan mẹta lo fara pa yannayanna
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Eeyan mẹta ti mọto tanka kan run mọlẹ ninu ṣọọbu ti wọn wa…