Abubakar di Judasi, o fa ọga ẹ le awọn ajinigbe lọwọ niluu Ọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Baba ẹni ọdun mejilelaaadọrin kan, Suleman Abubakar, lọwọ ti tẹ fun  lilu ọga…

Wahala n bọ o, Ṣoworẹ fẹẹ gbena woju Deji Akurẹ, eyi lohun to ṣẹlẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gbajugbaja ajafẹtọọ ọmọniyan nni, Ọmọyẹle Ṣoworẹ, ti fa ibinu yọ si Deji tilu…

Iru ọmọ wo waa leyii, o si binu pa iya ati aburo rẹ

Ẹka ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Enugu, ni ọkunrin kan, Somadina Orji, wa bayii, latari bo ṣe pa…

Aarẹ Ọnakakanfo, Iba Gani Adam’s, fẹyawo keji

Adewale Adeoye Ẹsẹ ko gbero nile awọn baba iyawo tuntun, Omidan Joy Onojaife, ti Aarẹ Ọnakakanfo ilẹ gbogbo Yoruba, Iba  Gani…

Azeez tun n pada lọ sọgba ẹwọn to ti de, ọmọ to fipa ba lo pọ lo ku mọ ọn labẹ

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajo Balogun tile-ẹjọ Majisireeti kan to wa niluu Yaba, nipinlẹ Eko, ni wọn foju Ọgbẹni Tajudeen Azeez, ẹni ogun…

Ẹ gba mi o, iyawo mi fẹẹ pa mi, ọbẹ lo fi maa n le mi kiri-Moshood

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinle Ọyọ ni awọn tọkọ-taya meji kan, Ọgbẹni Moshood Kani ati iyawo…

‘Iyawo mi n fẹsun agbere kan mi, niṣe lo maa n yẹ abẹ mi wo, ẹ tu wa ka’

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọpọ igbeyawo lo n daru nitori pe awọn ọkọ n fiya jẹ awọn…

Oju ole ree, waya ina ijọba ni wọn n ji ka tọwọ ba tẹ wọn

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ajọ aabo ara ẹni laabo ilu ti wọn n pe ni sifu difẹnsi, ‘Nigeria Security And Civil Defence Corps’ (NSCDC),…

Eyi le o, NDLEA ya bo ibi igbeyawo, wọn mu ọkọ iyawo lọ

Adewale Adeoye Ni agbegbe kan ti wọn n pe ni Shola Quarters, niluu Katsina, nibi ti…

Awọn agbebọn ji tọkọ-taya gbe sa lọ n’Ikorodu

Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n koroyin yii jọ lọwọ, awọn ọlọpaa agbegbe kan ti wọn n pe…

Baba Adeboye sọ asọtẹlẹ nipa iku rẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Adewale Adeoye Adewale Adeoye Pasito agba tijọ Onirapada nni, ‘The Redeemed Christian Church Of God’ RCCH, Pasitọ Enoch Adejare Adeboye, ti sọ pe bi gbigba…