Ọlanrewaju Adepọju, ọga awọn akewi jade laye

Ọlawale Ajao, Ibadan Ni nnkan bii aago meje alẹ ọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kẹwaa, oṣu Kejila,…

Ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un Naira ni mo ta ori ati ọwọ akẹkọọ Fasiti Ifẹ ti mo pa- Akeem

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa ni Eleweeran, niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, ni Ọgbẹni Akeem Usman wa, nibi to ti n ran wọn…

Wahala n bọ o! Portable olorin ati ṣọọṣi Sẹlẹ fẹẹ gbena woju ara wọn

Monisọla Saka Ọrọ ti wọn pe lowe ti n laro ninu bayii pẹlu bi Portable olorin,…

Abẹṣẹẹ-ku-bii-ojo lọkọ mi, o ti feẹ fi lilu ba aye mi jẹ, mi o fẹ ẹ mọ– Naimọt 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Kootu kọkọ-kọkọ to wa lagbegbe Wáráh, niluu Ilọrin, ipinlẹ Kwara, ni obinrin ẹni…

Aṣiri tu! Ajulọ ni ayederu ibuwọlu Akeredolu lawọn ọmọlẹyin rẹ fi n ṣe oriṣiiriṣii nnkan

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Agba agbẹjọro lorilẹ-ede yii, Amofin agba Kayọde Ajulọ, ti fẹsun kan awọn ọmọlẹyin…

Iru ki waa leleyii, ọkọ tẹ ọlọkada kan pa l’Óbòtò

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọlọkada kan ti  pade iku ojiji loju ọna marosẹ Ondo si Akurẹ, laaarọ…

 Akeredolu gbọdọ gbejọba fun igbakeji rẹ-Ẹgbẹ PDP

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party (PDP), nipinlẹ Ondo, ti ni ọna abayọ kan…

Ọmọ Naijiria yii ti daran niluu Oyinbo o, wọn ti mu un sọ satimọle

Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n koroyin yii jọ lọwọ, ọdọ awon alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Newmarket, niluu Suffolk, lorile-ede UK, ni…

O gbẹnu tan! Nibi tawọn ọlọpaa mẹrin yii ti fẹ gbowo itusilẹ lori ẹni ti wọn ji gbe lọwọ ti tẹ wọn

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Rivers, ti fọwọ ofin mu awọn ọlọpaa mẹrin kan ti wọn lọwọ ninu bi wọn…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Sunday Igboho

Faith Adebọla Ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ karun-un, oṣu Kejila yii, ni ile-ẹjọ kan ti wọn…

Wahala iyawo mi ti pọ ju ni mo ṣe fẹyawo keji, mi o ṣe mọ- Kazeem

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ Ọyọ, ni awọn tọkọ-taya meji kan, Ọgbẹni Kazeem Jẹjẹ ati Abilekọ Kafilat Jẹjẹ, gbe ara…