Adewale Adeoye Wọn ti mu iyaale ile kan to ti bimọ meji, ṣugbọn ti ko si nile ọkọ to…
Category: Ìròyìn
Ọwọ ti ba meji lara awọn ajinigbe to lọọ ji awọn oṣiṣẹ potiri n’Itele
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun, ti sọ pe ọwọ ti tẹ meji lara awọn ajinigbe mẹfa kan ti wọn…
Dukia Kwara Hotel lawọn eleyii lọọ ji ko tọwọ fi tẹ wọn n’llọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, araalu to n lọ bii ogun niye, ni wọn ti…
Falana fẹẹ farugbo ara ṣẹwọn, ọmọọdun meje lo fipa ba sun l’Ekiti
Faith Adebọla Bi wọn ba n ṣadura keeyan ma ri idaamu lọjọ alẹ rẹ, boya ni…
Aye ma nika o! Lẹyin tawọn ọdaran yii gbowo itusilẹ tan ni wọn ri alaga kọmuniti mọlẹ laaye
Faith Adebọla Ọtafa-soke yido-bori, b’ọba aye ko ri ọ, tọrun n wo ọ. Ọrọ ikilọ yii…
Adajọ ni ki Reuben lọọ ṣe Keresi at’ọdun tuntun lẹwọn, eyi lohun to ṣe
Faith Adebọla Ohun to daju bayii ni pe bi gbogbo eeyan ba n yayọ ọdun Keresi…
Eedi ree o! Ileeṣẹ ologun yin ado oloro pa eeyan marundinlaaadọrun-un wọn lawọn ro pe Boko Haram ni wọn
Faith Adebọla Owe Yoruba to ni ogun ni i ṣi’ni i mu, epe ki i ṣi’ni…
Ọpẹ o, wọn yoo bẹrẹ si i wa epo rọbi nipinlẹ Ogun laipẹ– Abiọdun
Faith Adebọla Bi ohun gbogbo ba lọ bi wọn ṣe gbero rẹ, ipinlẹ Ogun ko ni…
Eyi tun ga o, onikẹkẹ Marwa ti wọn ni ko gbe awọn ọmọ mẹrin lọ sileewe gbe wọn sa lọ
Adewale Adeoye Ko sẹni to maa ri bi Ọgbẹni Chimaobi Agah, baba awọn ọmọ ileewe mẹrin kan…
Ọkọ mi n lepa ẹmi mi pẹlu ada, mi o ṣe mọ-Kẹmi
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ Ọyọ, lawọn tọkọ-taya meji kan, Abilekọ Kẹmi Ọpẹbiyi ati Ọgbẹni Isaac Ọpẹbiyi, wọ ara wọn lọ. Abilekọ Kẹmi…
Portable olorin buga sawọn ọta ẹ, eyi niye ile to loun ti ni
Adewale Adeoye Gbajumọ olorin hipọọpu nni, Habeeb Okikiọla ẹni tawọn eeyan mọ si Portable ti tun bọ sita gbangba lati sọko…