Aisan to n ṣe Akeredolu kii ṣoju lasan-Wolii Ayọdele

Oluṣẹyẹ Iyiade Oludasilẹ ijọ INRI Evangelist Spiritual Church lorilẹ-ede yii, Primate Elijah Ayọdele, ti fero ọkan…

Nibi ti Bọde ti fẹẹ ji ọmọ ọlọmọ gbe ni wọn ti mu un l’Okitipupa Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Afurasi ọdaran kan, Bọde Agbedun, ti n jẹjọ lọwọ nile-ẹjọ Majisireeti kan to…

Ajalu buruku leleyii o! Ọba alaye mẹta waja lọjọ kan naa nipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo agbegbe Ogbomọṣọ, nipinlẹ Ọyọ, lo wa ninu ọfọ bayii pẹlu bi ọba…

Ajinigbe tun ji alufaa ijọ Katọliiki ati dẹrẹba rẹ gbe lọ

Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n koroyin yii jọ lọwọ, awọn ajinigbe kan ti wọn ji alufaa…

 Apoti ni mo fi fọ Abilekọ Adamọlẹkun lori nitori ariwo to n pa nigba ti mo fẹẹ ji foonu rẹ-Mubarak

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan ninu awọn ti wọn fẹsun kan pe wọn lọwọ ninu iku Abilekọ…

Eyi lohun tawọn ẹbi Mohbad gbọdọ ṣe ki n too le gba lati ṣayẹwo ẹjẹ fun ọmọ mi- Iyawo oloogbe

Faith Adebọla Yooba bọ, wọn ni, b’ina o ba tan laṣọ, ẹjẹ ki i tan leeekanna,…

Ibrahim yii ma laya o, mọṣalaṣi lo ti lọọ ji mọto onimọto gbe

Adewale Adeoye Ẹru tabi ipaya kankan ko ba ọmọkunrin kan ti wọn porukọ rẹ ni Ibrahim Mohammed, ẹni ọdun…

Wahala wa o, awọn agbebon ji Imaamu agba mọṣalasi, iyawo atawọn ọmọ rẹ lọ

Adewale Adeoye Titi di akoko taa n koroyin yii jọ, awọn agbebọn kan ti wọn waa…

Ẹlẹṣẹ ko ni i lọ lai jiya: Adajọ ni ki gende to fipa ba akẹkọọ ileewe girama meji sun maa lọ sẹwọn gbere

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Efiong Efion, tile-ẹjọ giga kan to wa niluu Eket, ipinlẹ Akwa-Ibom, ni wọn wọ Ọgbẹni Uduak Moses, ẹni ọdun mẹtadinlogoji, to fipa ba…

O ma ṣe o! Awọn adigunjale yinbọn pa oga oluṣiro owo lọfiisi gomina Ogun

Monisọla Saka Titi di ba a ṣe n sọ yii ni awọn eeyan ṣi n lọ…

Ojowu buruku: Iyaale ile la nnkan mọ ọkọ rẹ lori nitori to n ba obinrin mi-in sọrọ lori foonu

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Khadi Umar Sanusi Dan Baba, tile-ẹjọ ‘Sharia Court’, to wa niluu Kano, ni wọn foju iyaale ile kan,…