Nitori Pasuma ati Portable, oluṣọ ijọ Sẹlẹ gbena woju awọn ọmọ ijọ

Monisọla Saka Oluṣọ agba fun ijọ Celestial Church of Christ, to wa lagbegbe Ketu, nipinlẹ Eko,…

Aṣiri tu! Adajọ ju Seriki-n-Fulani Kwara sẹwọn gbere, wọn lọgaa awọn ajinigbe ni

Ile-ẹjọ giga to fikalẹ siluu Ilọrin, ti ni ki Seriki-n-Fulani ipinlẹ Kwara, Alaaji Usman Adamu, aburo…

Ọlọrun Ọba Oniṣẹ-ara: Iya aadọrin ọdun bi ibeji lanti-lanti!

Faith Adebọla Orin, “ẹ ba mi jijo ọpẹ o” ti gba ẹnu mama agbalagba ẹni aadọrin…

Nnkan de, baale ile bu sẹkun ni kootu: Fadeyi oloro niyawo mi, gbogbo ẹbi mi lo bẹru ẹ

Faith Adebọla Tiyanu-tiyanu ladajọ atawọn ero to wa ni kootu fi n wo baale ile kan,…

O doju ẹ, adajọ tun ran ọba alaye mi-in lẹwọ nipinlẹ Ogun

Faith Adebọla  Ootọ lawọn agba n powe pe ‘ori ade ki i sun’ta,’ amọ owe naa…

O ma ṣe o, nibi ti ọlọpaa yii ti n fi mọto le ọlọkada lọ nitori ẹgunjẹ lo ti  pa akẹkọọ to n lọ jẹẹjẹ ẹ

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun, nibi ti ọlọpaa kan, Ọgbẹni Sunday, ẹni tawọn eeyan tun mọ si Freedom, ti fi mọto…

O ma ṣe o, eeyan mẹẹẹdọgbọn jona ku ninu ijamba ọkọ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan mẹẹẹdọgbọn lo jona kọja idanimọ, ninu ijamba kan to…

Palietiifu: Adeleke kede afikun ẹgbẹrun mẹẹẹdogun Naira fawọn oṣiṣẹ ijọba

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati le mu itura ba awọn oṣiṣẹ ijọba nipinlẹ Ọṣun, Gomina Ademọla Adeleke…

Eyi tun ga o, ọmọbinrin yii pa ọmọ tuntun jojolo to bi

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Sango-Ọta, nipinlẹ Ogun, ti mu ọdọmọbirin kan torukọ rẹ n jẹ Esther Ojuko, o si ti n ran…

Lai fi ti bi ile-ẹjọ ṣe yọ ọ nipo ṣe, Ṣọun Ogbomọṣọ yoo ṣe ṣayẹyẹ iwuye

Ọlawale Ajao, Ibadan Lai fi ti pe ile-ẹjọ ti da a lọwọ kọ pe ko yee…

Emefiele ma waa rogo o, ṣẹyin naa ti gbọ ohun ti wọn tun ṣe fun un ni kootu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afi bii alaisan ti wọn da duro lọsibitu, ti wọn ni ara rẹ…