Adewale Adeoye Gbogbo mọlẹbi ti file pọnti, wọn ti fọna roka, wọn si ti fi agbada…
Category: Ìròyìn
O n rugboo bọ o, eeyan meji ku, mẹjọ fara pa yannayanna nibi ija awọn agbẹ ati Fulani darandaran
Adewale Adeoye Eeyan meji ni wọn padanu ẹmi wọn lojiji, nigba ti awọn mẹjọ miiran fara pa…
Owo ele ti mo ya nitori ileewe awọn ọmọ mi lọkọ mi lọọ fi ṣekore ni ṣọọṣi, mi o ṣe mọ
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinle Ọyọ, lawọn tọkọ-taya meji kan, Abilekọ Oluwatoyin Ilọri ati ọkọ rẹ, Ọgbẹni Fẹmi Ilọri, gbe ara wọn…
Baba Mohbad figbe ta: Ẹyin ọmọ Naijiria, ẹ ṣaanu mi, mo nilo owo lati fi ṣayẹwo ẹjẹ fọmọ oloogbe
Adewale Adeoye ‘Ẹyin ẹlẹyinju aanu ọmọ orilẹ-ede yii, ọrọ mi ko gbọdọ su yin rara, paapaa ju lọ lasiko…
Abiru ki leyii, awọn agbegbọn paayan kan, wọn ji ọgọrun-un gbe sa lọ niluu kan ṣoṣo
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n ko iroyin yii jọ lọwọ, paroparo ni gbogbo inu ilu kan…
Ori ade sunta: Ọba alaye atawọn ijoye rẹ dero ọgba ẹwọn Abolongo, l’Ọyọọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọrọ tawọn eeyan maa n sọ pe ori ade ki i sunta ko…
Eeyan mẹjọ ku, mẹfa fara pa, nibi ijamba ọkọ ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan mẹjọ ni wọn ti dagbere faye, tawọn mẹfa miiran…
Eyi laṣiiri to wa nidii ọmọ ẹgbẹ okunkun to ku sahaamọ wa l’Abẹokuta – Ọlọpaa
Faith Adebọla Awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti tanmọlẹ si ọrọ kan to n ja…
Ọdọọdun ni Tinubu ni ka maa gbaayan ṣiṣẹ ọlọpaa bayii-Ẹgbẹtokun
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọga agba patapata ileeṣẹ ọlọpaa nilẹ wa, Kayọde Ẹgbẹtokun, ti ni oun ti…
Nitori aaye igbọkọsi, ọmọ lanlọọdu gun ayalegbe baba rẹ pa
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n ko iroyin yii jọ lawọn ọlọpaa teṣan agbegbe Ilajẹ-Ajah, nipinlẹ Eko, ṣi n wa Ọgbẹni…
Ọwọ tẹ awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun to n daamu wọn ni Sango-Ọta
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa kan to wa niluu Sango-Ọta, nipinlẹ Ogun, lawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹta kan wa ti wọn ti…