Faith Adebọla Awọn alaṣẹ ileeṣẹ to n ṣoju ijọba ilẹ United Kingdom, (UK), nilẹ wa, iyẹn…
Category: Ìròyìn
Ileegbimọ aṣofin gbe abọ iwadii jade lori Onidaajọ Adepele Ojo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbimọ ti Olori ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ọṣun, Ọnarebu Adewale Ẹgbẹdun, gbe kalẹ lati…
Oju ole ree: Ẹ woju gende-kunrin to n ji ẹran ẹlẹran gbe laarin ilu
Adewale Adeoye Gende-kunrin kan lọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Benue ti tẹ bayii, lori ẹsun ole jija. Ẹran ẹlẹran ni…
Ileeṣẹ tawọn ọmọkunrin yii n ba ṣiṣẹ ni wọn ja lole
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọga ileeṣẹ aladaani kan, Ọgbẹni Isiaka Saheed, ti wọ meji ninu awọn oṣiṣẹ ẹ…
Awọn agbebọn tun ti ji awọn agbẹ mẹta mi-in gbe ninu oko wọn
Adewale Adeoye Ileeṣẹ sifu difẹnsi, ‘Nigeria Security And Civil Defence Corps’, (NSCDC) ẹka tilu Dutsinma, nipinlẹ Katsina, ti bẹrẹ igbesẹ lati gba awọn agbẹ mẹta kan tawọn…
Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Small Doctor olorin
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n ko iroyin yii jọ lọwọ, ko sẹni to le sọ ni…
Aburo Mohbad t’aṣiiri ni kootu: Mo mọ ẹni to pa ẹgbọn mi
Monisọla Saka Adura Alọba, ti i ṣe aburo ati ọmọ ti wọn bi le oloogbe Ilerioluwa…
O gbẹnu tan o, ẹgbọn baba Mohbad naa ti jade sọrọ, awọn ohun to sọ kọja bẹẹ
Adewale Adeoye Bi onifa kan ba gbe ọpẹlẹ rẹ ṣanlẹ to sọ pe ija to n lọ laarin ẹbi Baba Mohbad ati…
Owo ita di wahala laarin ọlọkada at’awọn agbero, ẹni kan ku
Adewale Adeoye Ṣe lọrọ di bo o lọ yago fun mi laaarọ kutukutu l’Ọjọru, Wesidee, ọjọ kejila, oṣu Kọkanla, ọdun 2023 yii, lagbegbe Akute ati Alagboole, nijọba ibilẹ Ifọ, nipinlẹ Ogun. Awọn ọlọkada…
Ayẹwo igbẹyin lati mọ ohun to pa Oloogbe Mohbad n lọ lọwọ l’Amẹrika- Ijọba Eko
Adewale Adeoye Ni bayii, ọkan pataki lara awọn agbẹjọro ijọba ipinlẹ Eko to n ri sọrọ ẹjọ gbajumọ olorin hipọọpu…
O ma ṣe o, awọn to n feeyan ṣoogun owo pa John ni Ọbantoko, oju ati ọwọ rẹ ni wọn ge lọ
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ọbantoko, niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, lawọn ti bẹrẹ iwadii lori b’awọn afini ṣoogun owo kan ṣe…