Ọkọ simẹnti Dangote tẹ ọpọlọpọ awọn eeyan pa l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko din lawọn eeyan bii mẹsan-an ti wọn pade iku ojiji laaarọ kutukutu…

Ganiyu ti jẹ eewọ, ọmọ bibi inu ẹ lo fun loyun, lo ba tun fẹẹ ba a ṣẹ ẹ

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa teṣan kan to wa lagbegbe Adatan, niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, ni baale ile kan, Ọgbẹni Ganiyu Aikole, to…

Alabi yii ma daju o, o si ṣa Sakiru ladaa pa mọ inu oko rẹ l’Ekiti

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti fi pampẹ ofin gbe ọkunrin odi kan, Sunday…

Ọrọ iyọnipo adajọ agba Ọṣun tun di wahala, tajutaju lọlọpaa fi tu awọn oṣiṣẹ kootu ka

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ kootu nipinlẹ Ọsun ti kede pe awọn ti bẹrẹ iyanṣẹlodi…

Eyi le o, awọn agbebọn ji nọọsi gbe l’Ọṣun, miliọnu mẹwaa ni wọn n beere

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Obinrin nọọsi kan, S. Ogunyinka, la gbọ pe awọn agbebọn ti ji gbe…

Emefiele di kọsitọma awọn adajọ ni kootu, eyi lohun to ṣẹlẹ nigba to tun foju balẹ-ẹjọ

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Hamza Muazu, tile-ẹjọ giga kan to wa niluu Abuja, ni wọn tun taari  gomina…

Oṣere yii pariwo: Ẹ ma ko ba mi o, ko si nnkan kan laarin emi ati MC Oluọmọ

Adewale Adeoye Gbajumọ oṣerebirin ilẹ wa nni, Ọmọwumi Ajiboye, ti sọ pe ko si ọrọ ifẹ ikọkọ kankan laarin oun ati ọga…

Bureeki mọto ayọkẹlẹ feeli, o ja wọle onile, eeyan mẹrin lo run mọlẹ

 Adewale Adeoye Eeyan mẹrin ti mọto ayọkẹlẹ kan run mọlẹ gidi ninu iyara ti wọn n sun…

Awọn to ji Aafaa Giwa gbe n’llọrin yari, wọn ni miliọnu mẹrin kere fawọn gẹgẹ bii owo itusilẹ 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Adura lo ku ti awọn mọlẹbi ọga ileewe aladaani kan, Aafaa Giwa, ti…

Fọlọrunsho kọja aaye ẹ, adajọ ti ni ko lọọ maa gbatẹgun lọgba ẹwọn Kirikiri

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ O.M Ajayi, tile-ẹjọ Majisireeti kan to wa niluu Ebute-Mẹta, nipinlẹ Eko, ni wọn foju Ọgbẹni Jẹgẹdẹ Fọlọrunshọ, ẹni ọdun mẹrinlelaaadọta…

Eyi nidi ti mo fi n lu iyawo mi atawọn ọmọ to bi fun mi nigba gbogbo- Lukuman

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Mallam Isiyaku Abdul Rahman, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ Sharia  kan to wa lagbegbe Magajin-Gari, nipinlẹ Kaduna, ni awọn tọkọ-taya…