Baba arugbo yii ṣe wọnda o, ọmọ ọdun mẹrindinlogun lo gbo mọlẹ titi to fi loyun

Ọlawale Ajao Lasiko to yẹ ko maa mura silẹ de ọjọ iku pẹlu iṣẹ rere, baba…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Abdullahi fada ge ọwọ ọrẹ rẹ bọ silẹ

Adewale Adeoye Ibinu ko mọ pe olowo oun ko lẹsẹ nilẹ lọrọ da fun ọkunrin kan,…

Awọn agbebọn ji nọọsi gbe l’Ọṣun, miliọnu mẹwaa ni wọn n beere

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Obinrin nọọsi kan, S. Ogunyinka, la gbọ pe awọn agbebọn ti ji gbe…

O ga o, eyi lohun tawọn ololufe Ta-ni-Ọlọrun ṣe fun un lẹyin to jade lẹwọn

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Beeyan ba gẹṣin ninu ajafẹtọọ ẹṣin Iṣẹṣe nni, AbdulAzeez Adegbọla, ti gbogbo eeyan…

 Mo mọ Akeredolu daadaa, ko le gba kẹnikẹni ṣe oun mọle to ba jẹ loootọ lara rẹ ti ya- Ẹníkúòmẹ̀hìn

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Agba ọjẹ kan ninu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party nipinlẹ Ondo, Amofin Benson…

Awọn eeyan bara jẹ gidigidi nibi isinku olukọ fasiti ti ọmọọdọ rẹ gun pa

Adewale Adeoye Beeyan ba jẹ ori ahun, to jẹ pe onitọhun daju ju nnkan mi-in lọ,…

Ileeṣẹ ọlọpaa Kwara ti mu ọmọ ẹgbẹ okunkun to ṣa akẹkọọ Poli Ọffa pa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Lọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kọkandinlogun, oṣu Kọkanla yii, ni ileeṣẹ ọlọpaa ẹka tipinlẹ…

Nitori awọn ọrẹ ọmọ ẹ ti wọn lawọn fẹẹ sinku ẹ, Baba Mohbad fabinu yọ

Adewale Adeoye Ni idahun sọrọ to n lọ lori ẹrọ ayelujara, leyii tawọn ọrẹ Ọladimeji Alọba, Mohbad,…

Damilare ja wọ ile onile, o ko wọn lẹru lọ, diẹ lo ku kawọn araadugbo lu u pa

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ E.O Idowu, tile-ẹjọ Majisireeti to wa lagbegbe Isabo, niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, ni wọn foju Ọgbẹni Kọlajọ Damilare ba. Ẹsun…

Monsuratu pariwo: Ọdun karun-un ree t’ọkọ mi ko ti ṣojuṣe rẹ ninu ile mọ, ẹ tu wa ka

Adewale Adeoye Iwaju Adajọ S.M Akintayọ tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ…

Eyi le o! Wọn ni owo to le ni biliọnu mẹta ataabọ ni Sanwoolu fẹẹ fi ra lọfinda ati faanu

Monisọla Saka Oludije funpo gomina ipinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Action Democratic Congress (ADC), Ọgbẹni…