Iru aafaa wo waa ni AbdulGaniyu yii, ọmọ to n kọ ni kewu lo fẹẹ fipa ba lo pọ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majistreeti kan to filu Ilọrin ṣe ibujokoo ti paṣẹ pe ki wọn…

Nitori adajọ-agba ipinlẹ Ọṣun, awọn oṣiṣẹ kootu fẹhonu han

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gbogbo awọn adajọ, awọn amofin, awọn agbofinro atawọn araalu ti wọn ni ohun…

Awọn eleyii fẹẹ sa kuro ni Naijiria tipatipa, ẹ wo bi wọn ṣe fẹmi ara wọn wewu

Monisọla Saka Afurasi ẹni ọdun mejidinlogun kan, Michael Daniel, atawọn mẹta mi-in tọwọ tẹ lasiko ti…

Lori oku MohBad, oṣere yii sọko ọrọ sawọn  ọlọpaa Naijiria

Faith Adebọla Afaimọ ni ki i ṣe owe, “iwọn ni nnkan dun mọ” ni gbajugbaja oṣere…

Toyin gba iku oniku ku, awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun to fẹẹ pa ọrẹkunrin rẹ ko ri i ni wọn fi ṣa ọmọbinrin naa pa  

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Yoruba ni ole ko ni i ja agba ko maa ṣe e loju…

Eedi ree o, ọkunrin yii fipa ba ọmọọdun meji laṣepọ, o lọti toun mu yo lo fa a

Faith Adebọla Bawọn kan ṣe n rọjo eebu ati epe rabandẹ rabandẹ le afurasi ọdaran yii,…

Boko Haram lugọ de gomina yii, wọn pa ọlọpaa meji, awọn mẹfa ṣeṣe yannayanna

Faith Adebọla  Bi gomina ipinlẹ Yobe, Mai Mala Buni, ba fi Oriyọmi kun orukọ rẹ lasiko…

Ọlọpaa fofin de yinyin banga lakooko ọdun Keresi nipinlẹ Ogun

Adewale Adeoye K’ekun ile gbọ ko sọ fun t’oko, ki adan gbọ, ko ro foobẹ, ni…

Wahala n bọ o, Gomina Adeleke yọ adajọ to ran Rahman Adedoyin lẹwọn nipo

Florence Babaṣọla Oṣogbo Pẹlu bi nnkan ṣe n lọ, afaimọ ki wahala ma  ṣẹlẹ laarin ileesẹ…

O ma ṣe o! Wọn si pa ọga awọn oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Ọyọ yii sinu ile ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ ibanujẹ, eyi to kun fun ẹkun ati ipayinkeke lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ…

Eyi lohun ti Saidi Oṣupa sọ lasiko ikẹkọọ-gboye rẹ ni Fasiti Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo awọn ololufẹ orin Fuji kaakiri agbaye ni wọn ti n ki gbajugbaja…