Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ ibanujẹ, eyi to kun fun ẹkun ati ipayinkeke lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ…
Category: Ìròyìn
Eyi lohun ti Saidi Oṣupa sọ lasiko ikẹkọọ-gboye rẹ ni Fasiti Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo awọn ololufẹ orin Fuji kaakiri agbaye ni wọn ti n ki gbajugbaja…
Eyi lohun to ṣẹlẹ si Bọlanle Ninalowo niluu Ikorodu
Jọkẹ Amọri Owe Yoruba kan lo sọ pe ọmọ ẹni ki i ṣe idi bẹbẹrẹ ka…
Eyi nidi ti mo fi fẹran lati maa ṣira mi silẹ-Zainab
Faith Adebọla Bakare Zainab, arẹwa oṣere-binrin onitiata to niwaju ati akọyinsi daadaa nni, ti ṣalaye nipa…
Wọn ti mu ọmọ Naijiria to sa lọ siluu oyinbo yii, ẹṣẹ to ṣẹ kọja bẹẹ
Monisọla Saka Ọpọ ọmọ Naijiria ni wọn ti lọ siluu oyinbo ti wọn ri ohun mu…
Ẹ gba mi o, ọkọ mi gerun ori mi, o fẹẹ fi ṣoogun– Mariam
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin ‘‘Ẹni ta a fẹẹ sun jẹ tẹlẹ to tun n fepo para lọrọ…
A ti tu Naira Marley ati Sam Larry silẹ lahaamọ o – Ọlọpaa
Faith Adebọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tu awọn gbajumọ ọrẹ meji nni, Naira Marley ati…
Ẹ wo ohun ti Sanwo-Olu ṣe fawọn to n tọrọ baara l’Ekoo
Faith Adebọla Ọrọ ta a pe lọwe ti n laro ninu fun awọn akanda ẹda ti…
Emefiele ti rogo o, ile-ẹjọ ni ki wọn maa gbe e lọ sọgba ẹwọn Kuje!
Faith Adebọla Lai fi ti bi wọn ṣe yọnda beeli fun un lọsẹ to kọja yii…
Aye ma nika o! Wọn ṣa akẹkọọ Ọffa Poli pa sinu yara ẹ
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu ibẹru nla lawọn akẹkọọ ileewe gbogbonise tijọba apapọ to wa niluu Ọffa,…
Ile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun da Gomina Sanwo-Olu lare, wọn ni ko maa ṣejọba Eko lọ
Adewale Adeoye Ile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun kan to n gbẹjọ ti ondije dupo gomina ipinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ oselu ‘Peoples Democratic Party’ (PDP), Ọgbẹni Adediran, ẹni…