Adewale Adeoye Nitori bo ṣe fi ọmọ-odo fọ baba rẹ lori titi tiyẹn fi ku pẹlu…
Category: Ìròyìn
Ajalu buruku leleyii o! Olukọ Fasiti Ifẹ ṣubu lulẹ ninu ọfiisi, lo ba ku
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan lara awọn olukọ agba ni ẹka imọ ẹkọ, Faculty…
O ga o, lẹyin to lo bii oṣu mẹta lahaamọ, Ta-ni-Ọlọrun ti gba ominira patapata
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu Kọkanla yii, ni ile-ẹjọ Majisireeti kan to filu…
Olọrun lo fi Tinubu kẹ Naijiria bii mesayawa, a gbọdọ fara da inira yii – Oluwoo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti sọ pe Ọlọrun lo…
Banki apapọ ilẹ wa ti sọrọ: Owo atijọ ko ti i kasẹ nilẹ, ẹ maa na an lọ
Monisọla Saka Awọn alalṣẹ olori banki apapọ orilẹ-ede yii, Central Bank of Nigeria (CBN), ti kede…
Ọwọ pada tẹ Tosin, olori ọmọ ẹgbẹ okunkun to n yọ wọn lẹnu n’Igbọkọda
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọmọ ogun oju-omi nipinlẹ Ondo, ti fi pampẹ ofin gbe afurasi ọmọ…
Nitori to sọ ootọ ọrọ nipa ijọba Tinubu, wọn gbaṣẹ lọwọ ọga ẹṣọ oju popo ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ootọ lowe Yoruba to ni oloootọ ki i lẹni, owe yii lo ṣẹ…
Ọkọ Salawa Abẹni fẹyinti lẹnu iṣẹ aṣọbode, eyi loun ti Waka Queen sọ nipa rẹ
Faith Adebọla Awọn to kọkọ ri ọba orin Waka Queen, Salawa Abẹni, ninu oṣu Kin-in-ni, ọdun…
Emi ni mo n gbọ gbogbo bukaata ninu ile, ọkọ mi tun n fẹsun agbere kan mi, ẹ tu wa ka- Rashidat
Adewale Adeoye Iwaju Adajọ Hammed Ajumọbi, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan ti wọn n pe ni Area-Court, to wa ni Centre-Igboro, niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ni…
O ma ṣe o, kọntena ṣubu le mọto akero ati kẹkẹ Marwa mọlẹ, eeyan mẹrin lo ku
Adewale Adeoye Beeyan ba jori ahun, bo ba ri bi tirela kan to gbe kọntena sẹyin…
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun paayan kan lasiko ti wọn kọju ija sira wọn
Adewale Adeoye Ṣe lọrọ di bo o lọ o yago ni aṣalẹ ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹtala, oṣu Kọkanla yii, lagbegbe Ozoro, nijọba…