Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majisireeti kan to filu Ilọrin ṣe ibujokoo ti paṣẹ pe ki wọn…
Category: Ìròyìn
Akẹkọọ fasiti yii ma daju o, ọrẹbirin rẹ lo fun ni majele jẹ
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Suurulere, niluu Abẹokuta, nipinlẹ Ogun, ti mu akẹkọọ ‘Federal University Of Agriculture’ to wa niluu Abẹokuta, Ọgbẹni Ọladokun Ayọmide, nibi to ti n…
Oṣere yii pariwo: Ẹ gba mi o, gbogbo ẹru mi ni getimaanu ti mo gba ti ko lọ o
Monisọla Saka Gbajumọ oṣerebinrin ilẹ wa to lomi lara daadaa, tiwaju ati ẹyin rẹ ṣe deede…
Awọn agbebọn da ọkọ ijọba lọna ni wọn ba ji ọpọ awọn ero ko lọ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Titi di ba a ṣe n sọ yii ni wọn ṣi n wa…
Ọladimeji n rin ni bebe ẹwọn, ibọn agbelẹrọ ati ọpọ ọta ni wọn ka mọ ọn lọwọ
Adewale Adeoye Ọgbẹni Ọladimeji Hassan, ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn, kan tawọn ọlọpaa agbegbe Ojodu Berger, ka ibọn ilẹwọ agbelẹrọ kan ati ọpọlọpọ ọta ibọn mọ…
O ma ṣe o: Oṣu keji lẹyin iku Mohbad, ọdọmọkunrin olorin mi-in tun ku lojiji
Faith Adebọla Lẹyin bii oṣu meji ti Ọladimeji Ilerioluwa Alọba, ti ọpọ eeyan mọ si Mohbad…
Isọji ita gbangba ni wọn pe Sunday si, lo ba ku lakooko ti wọn n gbadura lọwọ
Adewale Adeoye Titi di akooko ta a n ko iroyin yii jọ, inu ọfọ ati ẹdun ọkan ni ẹbi Oloogbe Sunday…
Iya ọkọ mi lọmọ rẹ maa n kowo fun lati ba wa ra ounjẹ sile, mi o fẹ ẹ mọ-Salamọtu
Adewale Adeoye Iwaju Adajọ Hammad Ajumọbi, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan ti wọn n pe ni ‘Area Court’,…
A maa ṣewadii ẹsun pe ọlọpaa ti wọn lu bajẹ ji apoti ibo gbe sa lọ- Ileeṣẹ ọlọpaa
Ileeṣẹ ọlọpaa ilẹ wa ti sọ pe awọn maa too bẹrẹ iwadii lori ẹsun magomago ati…
O ma ṣe o, nibi ti iyaale ile yii ti n la awọn ọmọ ijọ rẹ meji to n ja ni wọn ti gun un pa
Adewale Adeoye Alabukun fun ni fun awọn olulaja, nitori ọmọ Ọlọrun la o maa pe wọn…
Eedi ree, iyaale ile yii fibinu fun ọmọ ẹ ni majele jẹ, o ni ko ni baba
Adewale Adeoye Gbogbo awọn to gbọ ọrọ iyaale ile kan, Abilekọ Sughshater Ushahemba, pe o pa ọmọ…