IWE IROYIN TO N ṢOJU ỌMỌ YORUBA NIBI GBOGBO
Nibi tawọn ọdọ yii kora jọ pọ si lawọn ṣọja ti dana ibọn fun wọn.
Ẹ wo bawọn ṣọja ṣe n yinbọn fun awọn ọdọ to n fẹhonu han tako SARS bii igba ti wọn wa loju ogun.
You must be logged in to post a comment.