Ṣẹyin naa ti gbọ ti ṣoja to binu para ẹ danu loju ogun Boko Haram

Aderounmu Kazeem

Ọkunrin sọja kan ti won ko darukọ ẹ la gbọ pe o fa ibọn ẹ yọ laipẹ yii, ki ẹnikẹni si too sunmọ ọn, niṣe lo yin in lura ẹ lori, lo ba ku patapata. Lara awọn t iwon koju awonm ọ̄o ogun afẹmiṣofo ni.

Awọn tiṣẹlẹ ọhun ṣoju wọn sọ pe ko too di pe ọkunrin yii gbẹmi ara ẹ lo ti kọ iwe pelebe kan silẹ, ninu ẹ naa lo ti ṣalaye ohun to fa sababi to fi da ẹmi ara ẹ legbodo.

Abẹ ẹka ileeṣẹ oloogun orilẹ-ede yii, eyi ti wọn pe ni Army’s 27 force Brigade ni Buni Gari nipinlẹ Yobe lọhun-un niṣẹlẹ buruku ọhun ti waye. Ọkan lara awọn ṣoja ilẹ yii to n gbogun ti awọn janduku Boko Haram gan-an ni wọn pe ọkunrin kọburu ninu iṣẹ oloogun yii.

 

About Alaroye

Journalist, Press man and News Researcher of the federal Republic of Nigeria

Check Also

Pasitọ Chibuzor fun awọn obi Deborah ni ile fulaati mẹrinla atawọn ẹbun mi-in

Monisọla Saka O da bii pe iku Deborah, ọmọbinrin ti awọn awọn kan juko pa, …

Leave a Reply

//ashoupsu.com/4/4998019
%d bloggers like this: