IWE IROYIN TO N ṢOJU ỌMỌ YORUBA NIBI GBOGBO
Aarẹ Muhammadu Buhari ti tun yan alaga ajọ eleto idibo ilẹ wa, Mahmood Yakubu, pada si ipo alaga ajọ naa.
Pẹlu anfaani tuntun yii, ọkunrin naa ni yoo tun ṣeto idibo ọdun 2023.
You must be logged in to post a comment.