Lonii, Ọjọbọ, Tọsidee, ni wọn sinku Tolulọpẹ Arotile, ọmọbinrin afẹronpileeni-jagun akọkọ ninu iṣẹ ọmọ-ogun ofurufu nilẹ yii.
Eyi naa waye ni iboji awọn ọmọ-ogun to wa niluu Abuja, nibi tawọn mọlẹbi ẹ, awọn ọgagun loriṣiiriṣii ati aṣoju ijọba ti ṣeto isinku fun un nilana iṣẹ to n ṣe ki ọlojọ too de.
Eyi ni awọn fọto eto isinku naa: