Arotile: Wọn ti fa awọn afurasi ati mọto wọn le ọlọpaa lọwọ

Ileeṣẹ ọmọ-ogun ofururu Naijiria ti fa awọn mẹta ti wọn fẹsun kan lori iku Tolulọpẹ Arotile le awọn ọlọpaa lọwọ.

Aworan awọn mẹtẹẹta ati mọto ti wọn fi kọlu oloogbe naa niyi.

Leave a Reply