Aisha Buhari mu iyawo Tinubu yika inu Aso Rock

Adewale Adeoye Ni imurasilẹ lati gbọpa aṣẹ gẹgẹ bii iyawo olori orile-ede yii, iyawo Aarẹ ilẹ…

Ohun to da mi loju ni pe ma a di aarẹ Naijiria-Peter Obi

Faith Adebọla Yoruba bọ, wọn lohun a fẹsọ mu ki i bajẹ, ohun ta a ba…

Zainab ran awọn ajinigbe si ọmọ aburo ẹ, o fẹẹ fi gba ogun miliọnu lọwọ wọn

Monisọla Saka Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kano, ti fi panpẹ ofin gbe obinrin afurasi ẹni ọdun marundinlaaadọta…

Awọn ero to ba wọ mọto wọn lawọn eleyii n ja lole

Adewale Adeoye Awọn ọdaran meji kan, Fọlaṣade Sholagbe, ẹni ọdun mẹrindinlogoji, ati Ṣeun Ọkẹ, ẹni ọdun…

Pasitọ Ajayi n lọ sẹwọn ba a ṣe kọwe rẹ, ọmọ tẹnanti rẹ lo fipa ṣe ‘kinni’ fun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ojiṣẹ Ọlọrun kan, Pasitọ Famakinwa Ajayi, ti gba idajọ ẹwọn ọdun mejidinlogun lati…

Ọmọ Yahoo mẹrin rẹwọn he ni Kwara, jibiti ni wọn lu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kọkanla, oṣu Karun-un yii, ni ile-ẹjọ giga kan to filu…

Albert ni kiyawo mu omi ti wọn fi wẹ oku ẹgbọn ẹ ti ko ba mo si iku ẹ

Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ilu Atani, nijọba ibilẹ Ogbaru, nipinlẹ Anambra, ti foju Ọgbẹni Albert Eligbue,…

Ọwọ EFCC tẹ ọmọ Yahoo mẹjọ, eyi lawọn nnkan ti wọn ba lọwọ wọn

Adewale Adeoye Mẹjọ lara awọn ọmọ Yahoo kan ti wọn n ṣe gbaju-ẹ lori ẹrọ ayelujara…

Ile-ẹjọ ni kiyawo to fẹẹ kọ ọkọ ẹ sile da owo-ori to gba pada fun un

Adewale Adeoye A ki i jẹ meji laba Alade ni adajọ ile-ẹjọ Sharia kan, Onidaajọ Malam…

Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ija ẹṣọ Amọtekun atawọn Hausa l’Atikankan

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lasiko ijaagboro to waye fun bii wakati kan aabọ gbako laarin ẹṣọ Amọtẹkun…

Ẹni kan ku, ọpọ fara pa nibi ija ẹṣọ Amọtekun atawọn Hausa l’Atikankan

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lasiko ijaagboro to waye fun bii wakati kan aabọ gbako laarin ẹṣọ Amọtẹkun…