Ba a ba sọ iwa ibajẹ ta a ri nileeṣẹ mọna-mọna ilẹ wa, omije aa ja bọ loju araalu- Ọga EFCC 

Adewale Adeoye Ẹni a gboju okun le ko jọ ẹni agba lọrọ ileeṣẹ mọnamọna nilẹ wa.…

Obi le di aarẹ Naijiria lọdun 2027-Tanko

Monisọla Saka Adari apapọ fun ikọ Obidient Movement, ti i ṣe ẹgbẹ awọn ti wọn n…

 Ẹgbẹ awọn to da ileeṣẹ ifọpo silẹ ni: Ẹ ma fun ẹgbẹ awọn alagbata niwee aṣẹ o, o lewu

Ẹgbẹ awọn to ṣe idasilẹ ileepo bẹntiroolu nilẹ wa ti wọn pe ni The Crude Oil…

Ilara lo n daamu Atiku, ko lohun gidi kan to fẹẹ ṣe fun Naijiria – Ọnanuga 

Adewale Adeoye Oludamọran Aarẹ Tinubu lori eto iroyin lorileede yii, Ọgbẹni Bayọ Ọnanuga, ti ni ilara…

Igbakeji aarẹ tẹlẹ, Ọṣinbajo, gba Tinubu nimọran lori bi nnkan ṣe ri ni Naijiria

Adewale Adeoye Igbakeji aarẹ orileede yii tẹlẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo, ti rọ ijọba orileede yii pe…

Ayẹwo ẹjẹ ṣe pataki ju ayẹyẹ ikomọ lọ – Don Jazzy

Monisọla Saka Nitori awọn aṣiri aṣemaṣe ti awọn eeyan n ṣe pẹlu bi ọkọ sẹ n…

Ọpẹ o, ọwọ tẹ awọn afurasi mẹta ti wọn ge ọlọkada lori n’llọrin 

L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹfa, oṣu Kọkanla, ọdun 2024 yii, ni ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, ṣafihan awọn…

Eyi nidi ti opo to n tanna fawọn ọmọ Naijiria ṣe n daṣẹ silẹ ni gbogbo igba-Adelabu

Monisọla Saka Minisita fọrọ ina lorilẹ-ede yii, Adebayọ Adelabu, ti ni airi itọju to yẹ, bi…

Ijọba Eko ti ṣọọṣi Ridiimu ati Sẹlẹ pa l’Ekoo, eyi lohun ti wọn ṣe 

Adewale Adeoye Nitori bawọn ileejọsin kan, atawọn ile igbafẹ mi-in ṣe n fariwo buruku tiwọn di…

Ọlọkada meje dero ẹwọn n’Ibadan, eyi lohun ti wọn ṣe

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọlọkada meje ti dero ahamọ ọgba ẹwọn Agodi, n’Ibadan bayii. Odidi ọjọ mẹsan-an…

Awọn alagbata epo gbe Dangote lọ si kootu, wọn ni dandan ni kawọn maa ra epo l’Oke-Okun

  Jọkẹ Amọri Awọn alagbata epo gbe Dangote lọ si kootu, wọn ni dandan ni kawọn…