Oju ole ree: Lati ipinlẹ Anambra ni Chidi ati Obinna ti wa n ja ọkada gba l’Owode Yewa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin ti wọn ti wa si Owode Yewa lẹẹmẹta, ti wọn si ti…

Ẹ gba mi o: awọn ọlopaa SARS ti ọmọ mi mọle nitori owo biribiri ti wọn fẹẹ gba ti ko fun wọn

Ile-ẹjọ giga Eko lo pariwo lọ o. Obinrin oniṣowo Eko kan, Regina Stanley ni. O pariwo…

Eemọ ree o: wọn ni gomina ilẹ Hausa kan ni olori awọn Boko Haram

Ọkunrin kan to ti fi igba kan jẹ igbakeji ọga pata ni ileefowopamọ apapọ ilẹ wa…

Ẹyin ọmọde, ẹ le awọn arugbo wọnyi kuro nile ijọba, Ọbasanjọ lo sọ bẹẹ

Olori ilẹ wa yii nigba kan, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti sọ pe bi awọn ọdọ, awọn…

Ijọba Makinde ṣefilọlẹ ọja Akẹsan tuntun niluu Ọyọ

Tilu-tifọn ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, fi ṣefilọlẹ Ọja Akẹsan tuntun, niluu Ọyọ, eyi…

Wọn le ọga-agba Yunifasiti Eko lẹnu iṣẹ, ṣugbọn Purofẹsọ ta ku, o loun o lọ

Igbimọ apaṣẹ pata fun ile-ẹkọ giga yunifasiti Eko (University of Lagos) ti le ọga-agba ileewe naa,…

Konikaluku fidi mọle, ko ni i si ipejọpọ fun ayẹyẹ Ọṣun Oṣogbo- Adebisi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari bi awọn to n lugbadi arun Korona ṣe n pọ si i…

Ọwọ tẹ awọn ọmọ ‘yahoo’ mejilelọgbọn niluu Ogbomọṣọ, akẹkọo fasiti lo pọ ninu wọn

Owe Yoruba kan lo sọ pe ọjọ gbogbo ni tole, ṣugbọn ọjọ kan bayii ni tolohun.…

Korona tun pa Alaga Ijọba Ibilẹ Idagbasoke Onigbongbo

Ọkan ninu awọn alaga ijọba ibilẹ nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Francis Babatunde Oke, to jẹ alaga Ijọba…

Wọn fẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba, wọn lo gbowo lọwọ awọn afẹmiṣofo

Wọn ti fi ẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba kan o, Ishaq Akintọla ti yunifasiti LASU,…

Sanwo-Olu ni yoo ṣaaju ipolongo ibo Akeredolu l’Ondo

Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe yẹ, Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu yii, ni  ẹgbẹ oṣelu…