Ofin ti yoo fiya jẹ obi ti ọmọ ẹ ba n sẹgbẹ okunkun n bọ l’Ekoo

Faith Adebola, Lagos Bi abadofin kan tawọn aṣofin Eko ti bẹrẹ iṣẹ lori rẹ bayii ba…

Akeredolu ṣe ifilọlẹ ikọ Amọtẹkun l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Ṣe ni papa iṣere Gani Fawẹhinmi to wa l’Alagbaka, niluu Akurẹ, kun fọfọ…

  A gbọdọ ṣewadii bawọn ijọba to lọ ṣe ta dukia araalu ni Kwara-Abdulrazaq

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni Gomina Abdulrahman Abdulrazaq tipinlẹ Kwara ṣe ifilọlẹ…

Ọkọ obinrin ti oju rẹ yatọ ti yọju o, o loun ko kọ iyawo oun o

Stephen Ajagbe, Ilorin Abdulwasiu Ọmọ-Dada, ọkọ obinrin toun atawọn ọmọ rẹ ni ẹyin oju to yatọ,…

Ohun ti Mimiko ko le fọdun mẹjọ ṣe, Akeredolu loun ti ṣe e o

“Bo ba ṣe pe ijọba to wa ni ipinlẹ Ondo yii tẹlẹ ṣe daadaa ni, a…

Bọọda onikẹkẹ Maruwa n lọ sẹwọn gbere ree o, nigba toun naa fipa ba ọmọ ọdun mẹrinla sun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ile-ẹjọ giga to wa lagbegbe Oke Ẹda ni ilu Akurẹ ti dajọ ẹwon gbere fun…

Ọmọge Barakat lo daja silẹ, ni Ayọdele ba ṣeeṣi gun Muhammed pa lAgeege

Awọn ọlọpaa ti mu Ẹniọla Ayọdele ati Kayọde Babaṣọla ni Dọpẹmu, Ageege, nitori pe wọn gun…

Wọn le olukọ-agba ti ko wa sileewe lọjọ Isinmi kuro lẹnu iṣẹ lEkiti

Ijọba ipinlẹ Ekiti ti le Olukọ-agba (Principal) ileewe girama, Methodist Girls High School, Ifaki Ekiti kuro…

Makinde le ọkan ninu awọn kọmiṣanna rẹ danu

Lẹyin wakati diẹ ti o ti igbele Korona de, Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti…

O ṣẹlẹ! Wọn ni Wolii Festus fẹẹ fọmọ wolii ẹgbẹ ẹ ṣoogun owo l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni awọn agbofinro ko Wolii kan, Adebayọ Festus,…

Alainitẹẹlọrun ati alaṣeju ni Agboọla Ajayi -Kennedy

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbakeji Gomina Ondo, Agboọla Ajayi, ti tun kuro ninu ẹgbẹ oṣelu PDP, o…