Ta lo n purọ: Owo dija silẹ laarin Gomina Makinde ati ileewosan UCH

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo aye lo n fi ijọba ipinlẹ Ọyọ atawọn alaṣẹ UCH, iyẹn ileewosan…

Kayeefi nla leleyii o! Baba fun ọmọ bibi inu ẹ ẹ loyun n’Ikorodu

Chibuike naa tun fipa bọmọ ọdun mẹrinla lo pọ ni Bariga Bẹẹ ni Chinedu ṣe kinni…

Eyi ni bi aarẹ ẹgbẹ Rotaract Club ilu Iwo ṣe ku nibi to ti n gba bọọlu

Florence Babaṣọla, Osogbo Bii ala lọrọ naa ṣi n jẹ loju gbogbo awọn eeyan ilu Iwo,…

Wọn ṣi n wa awọn arinrinajo mẹjọ ti wọn ji gbe ni Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn agbofinro atawọn ẹṣọ alaabo lẹlẹka-jẹka ṣi…

Ajọ OYTMA gbẹsẹ le mọto ijọba ipinlẹ Ọyọ, wọn lo da gosiloo silẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan “Bi gbogbo aye ba n ṣe bayii, a dun”. Eyi lọrọ ti ọpọ…

Ọwọ ọlọpaa ti tẹ mẹta ninu awọn adigunjale to yinbọn pa Afaa Jamiu l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn afurasi mẹta kan lori Afaa kan ti wọn…

Dele ti jẹwọ fawọn ọlọpaa pe oogun owo loun fẹẹ fi pata obinrin toun mu ni Warewa ṣe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni kete tawọn ọlọpaa ba pari ifọrọwanilẹnuwo ati iwadii ti wọn n ṣe…

Awọn ọlọkada yari l’Abẹokuta, wọn ni apọju ẹgbẹ ko jẹ kawọn jere

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe Gomina Dapọ Abiọdun sọ pe o ṣee ṣe koun…

Rẹmi jẹwọ ni kootu, o ni koun le rowo tọju iya atiyawo oun loun ṣe n jale

Florence Babaṣọla, Osogbo Ifamoyegun Rẹmi, ẹni ọdun mejidinlogoji, ni aṣoju ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti taari…

Ijọba fi oṣu mẹfa kun igbele awọn alaga kansu fẹsun ṣiṣe owo ilu baṣubaṣu

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin ti oṣu mẹfa akọkọ tijọba fi jawee gbele-ẹ fawọn alaga ijọba ibilẹ…

Awọn mọlẹbi Olufalayi tawọn kan lu pa l’Ado-Ekiti n beere fun idajọ ododo

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Inu ọfọ nla lawọn mọlẹbi ọkunrin ẹni ọdun marundinlaaadọta kan, Olufalayi Ọbadare, wa…