Ẹ̣ wo bawọn ṣọja ṣe doju ibọn kọ awọn ọdọ ni Lekki

Nibi tawọn ọdọ yii kora jọ pọ si lawọn ṣọja ti dana ibọn fun wọn.

Ẹ wo bawọn ṣọja ṣe n yinbọn fun awọn ọdọ to n fẹhonu han tako SARS bii igba ti wọn wa loju ogun.

Leave a Reply

%d bloggers like this: