Ninu ibo gomina ti wọn di ni ipinlẹ Ẹdo lanaa ode yii, awọn esi lati ijọba ibilẹ ti wọn ti ka ni akayanju bayii, Gomina Godwin Ọbasẹki lo wọle julọ. Ijọba ibilẹ mẹtala ni esi wọn ti jade, ninu awọn mẹtala naa, Ọbasẹki to n dije lorukọ ẹgbẹ APC ti mu mọkanla, nigba ti ẹni to n ba a du ipo naa, Pasitọ Ize-Iyamu ti mu meji pere. Lapapọ, o ti le ni ẹgbẹrun lọna ọgọta ibo ti Ọbaseki fi ju Ize Iyamu lọ. Lati ipinlẹ marun-un lo ku t iwon tin reti esi idibo bayii, lẹyin naa ni ajọ INEC to n ṣeto idibo na ayo si kede ẹni to ba bori pata ninu wọn.
Bi wọn ti to esi idibo naa tẹ le ara wọn ree, ati awọn ijoba ibilẹ wọn:
- Esan West
APC 7,189
PDP 17,434
- Oredo LGA
APC 18,365
PDP 43,498
- 3. Etsako West LGA
APC 26,140
PDP 17,959
- 4. Ovia North East
APC 9,907
PDP 16,987
- 5. Esan South East
APC 9,237
PDP 10,565
- 6. Owan West
APC 11,193
PDP 11,485
- Owan East
APC 19,295
PDP 14,762
- 8. Egor LGA
APC 10,202
PDP 27,621
- 9. Uhunmwonde
APC 5,972
PDP 10,022
- 10. Ikpoba-Okha LGA
APC – 18,218
PDP – 41,030
- 11. Esan Central LG
APC 6,719
PDP 10,694
- 1 Esan North East LG
APC – 6,556
PDP – 13, 579
- 13. Igueben LGA
PDP – 7,870
APC – 5,199