Oluyinka Soyemi
Dundu iya ami-ayo mẹrin si odo ni Manchester United din fun Watford lalẹ yii nibi idije Premier League ilẹ England.
Raheem Sterling lo gba meji wọle fun Man City, nigba ti Phil Foden ati Aymeric Laporte ju ẹyọ kọọkan sawọn.
Nnkan ko rọgbọ fun Watford rara pẹlu bi wọn ṣe gbiyanju to ṣugbọn tọrọ yiwọ, afi bii igba ti wọn waa ta ẹpa lori papa.
Man city ti bọ sipo keji bayii lori tabili liigi naa, nigba ti Watford n sinmi nipo kẹtadinlogun.