Fidio: Ọwọ ti tẹ Fulani toun ati Muideen jọ pa awọn ọmọ ti wọn ji gbe l’Oṣogbo

Aye ma ti waa bajẹ o, ko si sọna tawọn eeyan ko le gba wa owo.
Ẹ wo Muideen, o si lẹdi apo pọ mọ awọn Fulani lati ji awọn ọmọ iyawo ẹgbọn rẹ gbe l’Oṣogbo, ọjọ kẹrin ti wọn ti n beere owo lawọn ọmọ mejeeji ku sinu igbo.

 

Leave a Reply