Florence Babaṣọla
Akinrun tiluu Ikirun, Ọba Rauf Ọlayiwọla Ọlawale, ti waja.
Alẹ Ọjọruu, Wẹsidee, mọjumọ Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii la gbọ pe baba dara pọ mọ awọn baba-nla rẹ.
Ọdun 1990 ni baba yii gun ori itẹ, ileefowopamọ lo si ti n ṣiṣẹ ko too jọba.