O maa ṣe o! Olori oṣiṣẹ lọfiisi gomina Kwara ti ku o

Stephen Ajagbe, Ilorin

Iroyin kan to tẹ wa lọwọ sọ pe Alhaji Aminu Logun ti i ṣe olori awọn oṣiṣẹ lọfiisi gomina ipinlẹ Kwara ti jade laye.

Ileewosan kan niluu Ilọrin ni wọn lọkunrin naa ku si lonii, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee.

Ohun ta a gbọ ni pe o ṣee ṣe ko jẹ arun Korona lo pa a.

About admin

Check Also

Ọmọọdun mẹtala ti Ayọbami n ṣe lẹsinni fun lo fipa ṣe ‘kinni’ fun l’Agọ-Iwoye

Gbenga Amos, Abeokuta Afaimọ ki ọkunrin ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn yii, Ayọbami Oluwatobilọba Runsewe, ma ti …

Leave a Reply

//zeechumy.com/4/4998019
%d bloggers like this: