Ọga ọlọpaa patapata nilẹ wa, Muhammed Adamu, ti gbẹsẹ le ẹka ileesẹ ọlọpaa ti wọn gbe kalẹ lati maa gbogun ti idigunjale ti wọn n pe ni SARS kaakiri gbogbo ipinlẹ to wa ni Naijiria. O ni eegun wọn ko gbọdọ ṣẹ mọ. Ninu atẹjade to fi sita llọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii lo ti kede ọrọ yii.
2 thoughts on “Ọga ọlọpaa patapata ti gbẹsẹ le SARS jake-jado Naijiria, o ni eegun wọn ko gbọdọ ṣẹ mọ”
Leave a Reply
You must be logged in to post a comment.
Well . Odara be . Sugbon ejekaro nu jinle nitori awon ajinigbe . Awon ole . Ki ijoba bawase agbekale . Todara lori atunse awon kidnapper ati awon ole pelu awo omo cut tiwongba ode kan ti. Afiki awon ijoba na bawawa nkanse si
O dara