Ọrẹoluwa Adedeji Ọmọkunrin to maa n mura bii obinrin, ti iwa ati iṣeṣi rẹ jọ ti…
Ileeṣẹ Dangote pariwo: Wọn fẹe ba wa lorukọ jẹ ni o, eyi niye ti a n ta epo bẹntiroolu tiwa
Jọkẹ Amọri Owe Yoruba kan lo sọ pe nibi ti erin meji ba ti ja, koriko…
Ṣe Emefiele yo bọ ninu wahala to wa yii ṣa, eyi lohun ti adajọ ni ki wọn ṣe fun un
Adewale Adeoye Ba a ba reeyan to sọ pe ọga agba banki apapọ orileede yii tẹlẹ,…
O yẹ kawọn araalu maa gboṣuba fun Tinubu, ki i foju kan oorun lori ọrọ Naijiria- Sunday Dare
Adewale Adeoye Olubadamọran Aarẹ Tinubu nipa eto iroyin ati iṣẹ akanṣe lorileede yii, Ọgbẹni Sunday Dare,…
Ṣẹyin naa ti gbọ ohun ti Toyin Abraham sọ nipa ọmọ Iyabọ Ojo
Jọkẹ Amọri Ki i ṣe tuntun mọ pe Priscilla, ọmọ Iyabọ Ojo, oṣere ilẹ wa…
Aburo Ayọdele Fayoṣe pariwo: Bi ohunkohun ba ṣe mi, ẹgbọn mi ati gomina Ekiti ni kẹ ẹ mu o
‘’Gbogbo ẹyin ọmọ Naijiria, bi ohunkohun ba ṣe mi pẹnrẹn, ẹgbọn mi, Ayọdele Fayoṣe ati gomina…
EFCC ti tu Bobrisky silẹ o, o loun ko ba ẹnikankan sọrọ
Ọrẹoluwa Adedeji Ni bayii, ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu…
Idaamu Bobrisky, EFCC ti tun mu un ju sahaamọ
Jọkẹ Amọri O jọ pe ọrọ awọn wolii ti wọn riran si ọmọkunrin to maa n…
Ọmọ ‘Yahoo’ marunlelaaadọta ha sakolo EFCC n’llọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ko din ni gende marunlelaaadọta (55), tọwọ ajọ to n gbogun ti iwa…
Ẹgbẹ awọn gomina sọ fun NNPCL: Ẹ yee mowo ile lọ sita, ẹ ṣatilẹyin fun ileeṣẹ epo Dangote
Ọrẹoluwa Adedeji ‘’A ki i ni ọkọ nilẹ ka maa fi ọwọ ko igbọnsẹ, ba a…
Ọwọ aṣọbode tẹ dẹrẹba oniṣowo to n ta ayederu oogun nipinlẹ Ọyọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Awakọ gbajumọ oniṣowo oogun kan nigboro Ibadan, ti dero ahamọ awọn ọlọpaa bayii.…