Ọga ọlọpaa fofin de POS ni ayika teṣan

 Monisọla Saka Ọga ọlọpaa patapata lorile-ede Naijiria, Inspector General of Police (IGP), Kayọde Ẹgbẹtokun, ti paṣẹ…

Awọn agbebọn ya wọ ile-iwe kan ni Kaduna, wọn ko ọpọlọpọ akẹkọọ ati olukọ lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade Awọn agbebọn ya bo ileewe alakọọbẹrẹ kan to wa niluu Kuriga, nijọba ibilẹ Chikun,…

Nitori Sisi Quadri, Baba Lawori ṣepe fawọn onitiata ẹgbẹ ẹ

Monisọla Saka Gbajumọ oṣerekunrin ilẹ wa to maa n fi ede Awori ṣawada, to si maa…

Bi Buhari ṣe tẹ owo Naira lọpọlọpọ nigba to n ṣejọba lo jẹ ki gbogbo nnkan wọn-Wale Ẹdun

Faith Adebọla Ọrọ owo ọja to gbowo leri gegere lasiko yii ti tun gba ọna mi-in…

Ẹ mu suuru, atunto ta a n ṣe si eto ọrọ-aje maa fi Naijiria lọkan balẹ laipẹ – Tinubu

Faith Adebọla Olori orileede wa, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ti rọ awọn ọmọ Naijiria lati ni…

O ṣẹlẹ! Ija buruku laarin Laide Bakare ati Ẹniọla Badmus

Monisọla Saka Ọrẹ ni wọn pe awọn mejeeji tẹlẹ, ileewe kan naa ni wọn lọ, oṣere…

Ijọba wo awọn ṣọọbu kan danu n’llọrin, wọn ni wọn kọ ọ sibi ti ko tọ 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu ironu nla ati iporuuru ọkan lawọn eeyan to n taja lawọn ṣọọbu…

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Isaac, ọmọkunrin marun-un lo ko wọ Ọṣun lati Akwa Ibom

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ikọ ẹṣọ alaabo Amọtẹkun ti tẹ ọmọkunrin ọmọ bibi ipinlẹ Akwa Ibom…

Eyi le o! Obinrin kan da ọmọ mẹta silẹ niwaju teṣan ọlọpaa, lo ba lọọ binu para ẹ  

Monisọla Saka Abilekọ kan ti ko sẹni to mọ orukọ, ile tabi ọna ẹ, ti ṣe…

Lẹyin iyanṣẹlodi oṣu mẹta, awọn oṣiṣẹ kootu pada sẹnu iṣẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lẹyin oṣu mẹta ti wọn ti jokoo sile, ẹgbẹ oṣiṣẹ kootu, (Judiciary Staff…

EFCC mu ọkọ mọkanlelogun to n ko ounjẹ lọ sorileede mi-in latilẹ wa

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, ọdọ ajọ to gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo…