Eeyan meje padanu ẹmi wọn nibi ti wọn ti n gba irẹsi tawọn kọsitọọmu n pin

Monisọla Saka Latari bi ilu ṣe le koko, ti ebi si n pa araalu, eeyan meje…

Wọn ri ọmọ ọdun meji he l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin kan to n bọ lati iṣọ-oru laago marun-un kọja iṣẹju mẹwaa aarọ…

Awọn fijilante pa ajinigbe kan, wọn ri meji mu, wọn tun gba obinrin meji ti wọn ji ni Kwara silẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Nnkan o ṣẹnuure fun awọn ajinigbe kan ti wọn ji eeyan mẹta gbe…

Ọwọ ọlọpaa tẹ awọn ajinigbe meji, wọn doola ọmọleewe ti wọn ji gbe

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn ole ajọmọgbe meji kan, Bọlajoko Haruna…

Ọmọ Yahoo fi mọto tẹ eeyan mẹta pa lasiko tawọn EFCC n le wọn ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Eeyan mẹta ni wọn ku l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanlelogun, oṣu Keji yii, l’Opopona…

Olumoro ti Moro, Ọba Abidoye Oyeniyi, ti waja

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọba Ezekiel Abidoye Oyeniyi, Arowooṣilejoye, ti i ṣe Olumoro ti Moro, nijọba ibilẹ Ariwa…

O ṣẹlẹ! Awọn ọlopaa n wa eegun to kan baba agbalagba lẹ́ṣẹ̀ẹ́ pa

Adewale Adeoye Ijọba ipinlẹ Anambra ti kede pe awọn n wa egungun adaṣọ-fun-jo kan to gbajumo daadaa…

Ọgbọn biliọnu Naira nijọba apapọ fawọn gomina lati yanju wahala ounjẹ to n fojoojumọ wọn-Akpabio

Adewale Adeoye Aipẹ yii ni Olori ileegbimọ aṣofin agba ilẹ wa niluu Abuja, Senetọ Godswil Akpabio, sọ pe ijọba apapọ ilẹ wa ti fun awọn gomina ipinlẹ kọọkan…

Wọn ti mu awọn eleyii, aṣọ ṣọja ni wọn fi n lu jibiti l’Ekoo

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ni awọn gende meji kan,  Jonathan Yahaya ati  Mohammed Umar, ayederu ṣoja ti ọwọ tẹ wa. ALAROYE…

Eyi lohun tileewe Fasiti KWASU sọ nipa akẹkọọ wọn to dawati

  Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn alaṣẹ Fasiti tipinlẹ Kwara (KWASU), Màlété, ti ni ọmọkunrin ẹni ọdun mẹrinlelogun…

EFCC foju gomina Kwara tẹlẹ, Abdulfatai Ahmed, bale-ẹjọ  

Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, ni ajọ to n gbogun iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu…