Wọn gba ayederu oṣiṣẹ LASTAMA yii mu l’Ekoo, owo nla to gba lọwọ onimọto lo ko ba a

Adewale Adeoye Yoruba bọ, wọn ni, ‘ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun’, bẹẹ gan-an lo ri fun ayederu oṣiṣẹ LASTAMA kan, Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina, ẹni ọdun…

O tan! Adajọ ti ju ayederu dokita to n lu araalu ni jibiti sẹwọn n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ giga kan to fi ilu Ilọrin ṣe ibujokoo, ti paṣẹ pe ki…

Ni bayii, lọọya Naijiria le ṣiṣẹ ni UK, gẹgẹ bi ti UK naa ṣe ti le ṣẹ ni Naijiria

Monisọla Saka Ijọba ilẹ United Kingdom, ti tọwọ bọwe ajọṣepọ pẹlu ilẹ Naijiria, lati le fawọn…

 O ma ṣe o, lẹyin bii oṣu kan aabọ ti wọn rọ ọ loye, alaga ẹgbẹ PDP tẹlẹ l’ Ondo ku lojiji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Alaga ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, (PDP) tẹlẹ nipinlẹ Ondo, Ọnarebu Fatai Adams,…

Damilọla yii laya o, ọlọpaa lo ja lole ni Ṣúpáre Akoko, o tun ji ibọn ẹ lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kayeefi patapata lọrọ ọmọkunrin kan ti wọn p’orukọ rẹ ni Arogubdade Damilọla, jọ…

Awọn ọlọpaa ti mu Sanni, wọn lo mọ nipa akẹkọọ-binrin Fasiti Akungba ti wọn gun pa laipẹ yii

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọlọpaa ti fi pampẹ ofin gbe afurasi ẹni ọdun mọkanlelogun kan, Olubọdun Sanni,…

 Awọn ọmọ Yahoo la lọọ ja lole tọwọ fi tẹ wa- Saliu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọmọkunrin ẹni ọdun mẹrinlelogun kan, Adeyẹye Saliu, lọwọ awọn agbofinro ti tẹ lẹyin…

L’Ọṣun, awọn oṣiṣẹ-fẹyinti ranṣẹ si Adeleke

Florence Babaṣọla, Ọṣogbo Awọn oṣiṣẹ ti wọn ti fẹyinti nipinlẹ Ọṣun, laarin ọdun 2011 si 2012…

Ijọba Kwara pe ipade apero lati gbogun ti lilo egboogi oloro

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulraman Abdulrasaq, lo ṣide ipade pataki kan, nibi ti wọn…

Adiẹ ti jẹ’fun ara wọn o: Umar pa Fulani ẹgbẹ ẹ l’Akoko, o lo n gbero lati ji oun gbe

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọmọkunrin ẹni ogun ọdun kan, Umar Ibrahim, lo ti wa nikaawọ ileeṣẹ ọlọpaa…

Oluwoo gba Tinubu nimọran: Ẹ ṣi bọda, ki ẹ si gbẹsẹ  lori fifofin de kiko ounjẹ wọle

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari wahala ọwọngogo ounjẹ to n mu awọn eeyan orileede Naijiria fojoojumọ pariwo,…