Monisọla Saka Oṣerebinrin ilẹ wa to maa n saaba ṣere oloyinbo, Halima Abubakar, ti bọ sita…
Tinubu juwe ile fawọn minisita rẹ marun-un
Monisọla Saka Gẹgẹ bi Aarẹ Bọla Tinubu ṣe bẹrẹ iṣẹ atunto laarin awọn to n ba…
Aarẹ Tinubu ti wọgi le awọn ileeṣẹ ijọba wọnyi
Monisọla Saka Aarẹ orilẹ-ede yii, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, atawọn igbimọ alaṣẹ ijọba apapọ, Federal Executive…
Wọn ti sọ ọmọ Naijiria yii sẹwọn ni Libya, eyi lohun to ṣe
Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lọwọ, ahamọ awọn agbofinro orileede…
Ki i ṣe Aarẹ Tinubu lo fa iyan ati ebi to gbalu kan lasiko yii – Akpabio
Adewale Adeoye Olori ileegbimọ aṣofin agba niluu Abuja, Senetọ Goodwill Akpabio, ti sọ pe biluu ṣe…
Ẹ fi Bobrisky lọrun silẹ, oun kọ lo ko ba Naijiria-Fayoṣe
Beeyan ba n ju oko siluu, yoo ni ọrẹ tiẹ, beeyan si n gunyan fun gbogbo…
Eyi laṣiiri ohun to faja laarin Portable ati Verydarkman
Ija buruku lo n lọ laarin ọmọkunrin olorin ti ẹnu ki i sin lara rẹ nni,…
Wọn ti da Bobrisky pada si Alagbọn
Ọrẹoluwa Adedeji Nibi tọrọ de duro bayii, Ọlọrun nikan lo le ko ọmọkunrin to maa n…
Nibi t’ọmọ ẹgbẹ okunkun yii ti fẹẹ ra ibọn lọwọ ti tẹ ẹ
Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Delta ti tẹ afurasi ọmọ ẹgbẹ okunkun kan, Amadasu Victor,…
A ko fẹ awọn onibaara niluu Abuja mọ, a maa bẹrẹ si i ko wọn- Wike
Adewale Adeoye Pẹlu ọrọ ti Minisita fun olu ilu ilẹ wa, Abuja, Ọgbẹni Nysome Wike, sọ…
Ijọba apapọ fẹẹ dawọ tita afẹfẹ idana s’Oke-Okun duro
Adewale Adeoye Lojuna ati le jẹ ki nnkan dẹrun fawọn araalu, paapaa ju lọ bi owo…