Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (10)

Ki i ṣe pe Ọba Zaria Jafaaru Dan Isiyaku lọgbọn kan lori to ju ti awọn…

Aarẹ wa balẹ si Bamako, ni Buhari ba bo imu ẹ pinpin

Aarẹ ilẹ wa, Ọgagun Muhammadu Buhari, ti balẹ si Bamako, lorileede Mali, nibi ti oun atawọn…

O ṣẹlẹ,  awọn aṣofin fẹẹ ran minisita yii lẹwọn

Olori ile-igbimọ aṣoju-ṣofin, Họnọrebu Fẹmi Gbajabiamila, ti ni ẹwọn n run nimu Minisita fun ọrọ agbegbe…

O digbooṣe, akọni obinrin wọ kaa ilẹ lọ

Wọn ti sinku Tolulọpẹ Arotile sibi ti wọn maa n sin awọn akọni si ni itẹkuu…

Baba ti wọn mu nitori wọn lọmọ ẹ n ja n’Ibadan ti ku sọdọ awọn ọlọpaa o

Ijẹsan-an lawọn ọlọpaa ti mu un, ni Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ to kọja. Wọn mu baba naa,…

O ma ṣe o! Eto isinku Tolulọpẹ ti bẹrẹ niluu Abuja

Lọwọlọwọ yii, wọn ti gbe oku ọmọdebinrin to jẹ ẹni akọkọ to n fi baalu-agbera-paa jagun…

Awọn ọmọ Naijiria gbe ẹgbẹ okunkun de’luu oyinbo, Italy ni wọn ti mu wọn

Awọn ọlọpaa orilẹ-ede Italy ti mu awọn ọmọ Naijiria mẹẹdogun kan ti wọn n ṣe ẹgbẹ…

Buhari n lọ si Mali loni-in o

Aarẹ Muhamadu Buhari yoo lọ si orilẹ-ede Mali loni-in yii. Ipade pataki kan lo n ba…

“Baba nla ole ati akowojẹ ni yin,” PDP lo sọ bẹẹ fawọn APC

  Ko si ẹgbẹ oṣelu kan to jẹ ẹgbẹ awọn ole ati akowo-ilu-jẹ to ju ẹgbe…

 Ibo abẹle Ondo:Ajayi ki Jẹgẹdẹ ku oriire, o loun tí gba f’Ọlọrun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Igbakeji gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Agboọla Ajayi, ti ki Eyitayọ Jẹgẹdẹ ku oriire…

IBO AWỌN PDP L’ONDO: JẸGẸDẸ WỌLE, AGBOỌLA JA BỌ!

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pẹlu gbogbo ilakaka Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ondo, Ajayi Agboọla, lati koju  ọga rẹ,…