Wọn ti bẹrẹ si i ka ibo ipinlẹ Edo

Wọn ti bẹrẹ si i ka ibo nipinlẹ Edo. APC n leri, wọn ni awọn yoo fẹyin PDP janlẹ.

PDP naa n leri, wọn ni Obaseki n pada bọ nile ijọba.

Ta lẹyin ro pe yoo yege lẹyin-o-rẹyin?

Leave a Reply

%d bloggers like this: