Olori awọn aṣofin Ọyọ jẹwọ: Makinde ni ko fọwọ si iṣẹ idagbasoke fun agbegbe Ibarapa

Ọlawale Ajao, Ibadan Abẹnugan ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ọyọ, Ọnarebu Debọ Ogundoyin, ti fidi ẹ mulẹ pe…

Ile-ẹjọ to ga ju lọ maa da ibo aarẹ to kọja yii nu bii omi iṣanwọ ni – Atiku

Faith Adebọla Oludije funpo aarẹ lẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDD, Alaaji Atiku Abubakar ti sọ…

Ọwọ ti tẹ Sulaimon, lẹyin to ji adiẹ ko n’Ijẹbu, lo tun lọọ ji jẹnẹretọ meji gbe

Faith Adebọla, Ogun Bi wọn ba sọ pe gende yii, Adegboyega Sulaimọn Adesanya, n rin ni…

Ọga ajọ eleto idibo gbọdọ fipo silẹ, o ta ibo wa ni-Ẹgbẹ Labour

Monisọla Saka Ọkan ninu awọn agbẹnusọ igbimọ eleto ipolongo ibo aarẹ fẹgbẹ oṣelu Labour Party, Kenneth…

Ẹwọn n run nimu Ṣẹgun atawọn ọrẹ ẹ, ẹru to lodi sofin ni wọn ba lọwọ wọn l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti wọ awọn ọrẹ mẹta kan wa sile-ẹjọ Majisreeti ipinlẹ…

Ko si nnkan kan laarin emi ati ọkọ Toyin Abraham o, awọn to sọ pe mo n fẹ ẹ fẹẹ ba mi lorukọ jẹ ni-Wumi Toriọla  

Jọkẹ Amọri Arẹwa oṣere ilẹ wa to maa n kopa onijangbọn ninu ere, tawọn eeyan si…

Dokita Adeyẹmi to pa ọrẹbinrin rẹ ati iyaale ile kan ti dero ẹwọn

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣẹ ẹ ranti ọkunrin dokita kan to sin oku ọrẹbinrin rẹ ati iyaale…

APC Ọṣun ni arumọje ni aṣeyọri ọgọrun-un ọjọ Gomina Adeleke, lawọn PDP ba ni iwọfa lẹnu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) ati Peoples’ Democratic Party (PDP) nipinlẹ Ọṣun…

Agba lọọya mọkandinlogun ni Atiku gba nitori ẹjọ ibo to gbe lọ si kootu

Monisọla Saka Oludije funpo aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu People’s Democratic Party (PDP), Alaaji Atiku Abubakar,…

Ẹgbẹ Akọọdu kọju oludije wọn soorun alẹ, wọn ni Makinde lawọn yoo dibo fun

Ọlawale Ajao, Ibadan O da bii pe omi ti gbẹ lẹyin ẹja Oloye Adebayọ Adelabu, oludije…

‘Adigunjale ni mi, mo tun n ṣẹgbẹ okunkun, ibọn meje ni wọn ka mọ mi lọwọ-Kinsely’

Faith Adebọla Ba o rẹni fẹyin ti, bii ọlẹ la a ri, ba o rẹni gbẹkẹ…