Eyi ga! Oludije funpo gomina fikunlẹ bẹ ẹ, o ni kawọn ọdọ jọwọ, dibo foun

Faith Adebọla Yooba bọ, wọn ni a ki i dọbalẹ ka ni’na loju. Asiko yii o…

Awọn ṣọja mu gende mẹta pẹlu kaadi idibo ẹgbẹrun kan aabọ ninu ile akọku

Faith Adebọla, Eko Pẹlu bi eto idibo sipo gomina ṣe ku ọsẹ kan bayii, ọwọ palaba…

Reluwee fori sọ bọọsi BRT l’Ekoo, eeyan meji ku, ọpọ fara pa yannayanna

Faith Adebọla O kere tan, eeyan meji ti pade iku ojiji, nigba ti ọpọ fara pa…

INEC ti sun eto idibo sipo gomina atawọn aṣofin ipinlẹ siwaju o

Faith Adebọla Ajọ eleto idibo apapọ ilẹ wa, Indepedent National Electoral Commission, INEC, ti kede pe…

Lẹyin ọjọ marun-un ti wọn ti n wa Elijah ni wọn ba a nibi to pokunso si

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kayeefi patapata lọrọ iku ọmọkunrin kan, Elijah Akinrinlọla, ṣi n jẹ fawọn ẹbi…

Eyi lohun tijọba mi ti ṣe laarin ọgọrun-un ọjọ l’Ọṣun-Gomina Adeleke

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, ti ṣeleri fun awọn araalu pe kesekese…

Wasiu ti dero kootu, ewurẹ nla kan lo ji gbe l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ti wọ ọkunrin ẹni ọdun marundilogoji kan, Adebayọ Wasiu, lọ sile-ẹjọ…

Ibo aarẹ: Eyi lawọn nnkan marun-un ti ẹgbẹ PDP n beere lọwọ INEC lati ṣe

Monisọla Saka Lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹfa, oṣu Kẹta, ọdun yii, ni ọga agba ajọ eleto…

Akinbinu ji ẹgbọn rẹ gbe, lẹyin to gbowo lọwọ molẹbi tan lo pa a l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Bi iku ile ko pa ni, tode ko le ri ni pa. Bẹẹ…

Banki apapọ paṣẹ fawọn araalu ati ileefowopamọ: Ẹ maa gba owo atijọ lọwọ onibaara

Adewumi Adegoke Banki apapọ ilẹ wa, Central Bank of Nigeria (CBN), ti paṣẹ pe ki awọn…

Awọn alatilẹyin Tinubu lọ si ọfiisi INEC, wọn ni eto idibo ti wọn ṣe daa gan-an ni

Ọrẹoluwa Adedeji Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ keje, oṣu Kẹta, ọdun yii, ni awọn to jẹ alatilẹyin…